IHINRERE
SYNQPTIKI
AFIHAN: Bi a ba
farabalc kiyesi Bibeli wa, a o ri wipe awqn iwe ihinrere mcrin ni o wa. Awqn
naa ni wqnyi:
Matthew
Marku
Luku
Johannu
Ni akoko ti won ze
akojqpq Bibeli ni wqn yq mcta ninu iwe yi ti wqn pe ni ihinrere synqptiki: Matthew,
Marku ati Luku.
Matthew, Marku ati
Luku, ninu iwe wqn, sqrq nipa ibi Jesu Kristi, (genealogy) ati baptisimu Jesu
Kristi, idanwo Jesu Kristi ti wqn si salaye izv iranzc Jesu Kristi lckunrcrc.
Ni tootq, ihinrere synqptiki tumq si awqn
iwe ihinrere mcta akqkq ti o jq ara wqn.
ALAYE
ITUMQ
IHINRERE SYNQPTIKI
Synqptiki wa lati inu ede Giriki ti a pe
ni ‘synqptikqsi’ ti o tumq si, riran
papq tabi hihun papq. Gbolohun qrq yi ni a lo fun awqn iwe ihinrere mctccta
akqkq tii ze Matteu, Marku ati Luku. Ihinrere ti synqptiki ni iwe ihinrere mcta
akqkq to jqra wqn. Awqn iwe ihinrere mctccta yi jqra wqn ni zize akqsilc igbe
aye Kristi, zugbqn iwe ihinrere kcrin (Johannu) yatq si wqn. Awqn iwe ihinrere
ti synqptiki duro lori orisun alakqsilc.
AWQN ORISUN IRANWQ
1. Orisun alafcnusq-
Eleyi jc orisun ifitonileti ti cnikan tumq rc fun clomiran.
2. Orisun alakqsilc-
Eleyi jc orisun ifitonileti ti cnikan fi fun clomiran lati le ze cda akqsilc
rc.
1.
Orisun
alakqsilv:
Orisun alakqsile jc orisun iranwq fun awqn ihinrere wqnyi lati qwq cnikan si
clomiran. Awqn ohun ti o wa ninu qrq wqnyi jqra wqn pupq. Isc iranzc Jesu ni a
ze agbekalc rc ninu ihinrere mctccta ni qna kan naa. Alaye inu rc jqra, ati
awqn ikqni Jesu ninu iwe ihinrere. Awqn ijqra yi farahan de ipele ede won, aza
ati awqn qrq inu rc. Amqza, akiyesi awqn iyatq ninu ijqra wqn yi, eyi ti o ze
afihan pe awqn iwe naa yatq si ara wqn ni igbekalc.
Niwqn igbati awqn ihinrere ti synqptiki gbckcle
orisun alakqsilc, ihinrere kcrin paapa naa gbckcle orisun alakqsilc de ipele
kan, zugbqn, orisun aza tirc jc alafcnusq. A ze afcnuzq qpq qrq ninu iwe
ihinrere kcrin.
Ni
itvsiwaju, igbagbq awqn onigbagbq akqkq yi ni yio sq iru aza wo ni wqn fv ti
wqn si gba pe o jc orisun iranwq fun awqn iwe yi. Siwaju sii, awqn baba igbagbq
ko ipa pataki lati fi idi orisun ti wqn gba kq awqn iwe yi mulc. Nitori pe ki a
to tcwq gba ihinrere gcgcbi orisun ckq igbe aye kristicni, awqn nkan wqnyi ni a
gbqdq kiyesi:
1. Akoko
ti wqn fi qrq naa sqwq nipa afcnusq
2. Ibazepq
laarin ihinrere synqptiki pclu ibazepq ti o zee ze ki o wa ninu ihinrere kcrin.
3. Iwoye
imq ijinlc, olukuluku awqn onkqwe.
Ifarabalv lati wadi
ibazepq ti o kan farahan ni a npe ni ORISUN IWADI, nigbati ifarabalv wadi akoko
ti a kq iwe naa ni a npe ni IWADI ALAGBELVRQ.
ORISUN
IWADI
Bi a ba yc ihinrere
wo, kii ze ihinrere mcta akqkq ni o yatq si ihinrere ikcrin, zugbqn o daju pe
awqn ohun ijqra wa laarin ihinrere ti synqptiki ati ihinrere ti Johanu bakanaa
ni awqn iyatq eyi ti awqn qjqgbqn ze iwadi rc.
Lati qgqrun
mejidinlogun ati mqkandinlogun odun (18th ati 19th Century) scyin, ni a
ti tcnu mq pe ki a farabalc ze idanilckq ninu majcmu titun, paapa julq, iyatq
ati awqn afijq ti o wa ninu awqn ihinrere mcta akqkq.
Awqn apapq akojqpq
iyato ati awon afijo ti o wa ninu iwe ihinrere mcta akqkq ni a npe ni IZORO SYNQPTIKI.
IZORO SYNQPTIKI
ALAYE
ITUMQ: Izoro synqptiki jc akojqpq awqn iyatq ati awqn
afijq ti o wa ninu awqn iwe ihinrere mcta akqkq. O jc ojuze akqkq fun iwadi
orisun lati gbiyanju qna abayq kuro ninu izoro synqptiki. Afijq larin iwe mcta
akqkq pin si qna meji:
1. Gbogbo
awqn ihinrere mctccta ni wqn ni akqsilc gbogbo nipa izc iranzc Jesu.
2. Gbogbo
wqn bcrc pclu akqsilc igbe aye Johannu baptisi ati idanwo Jesu.
Wqn tcsiwaju pclu
akqsilc izc iranzc Galili ati akqsilc irin ajo lq si kesaria ti Filippi, kii ze wipe akqsilc ihinrere yi jqra wqn nikan, zugbqn
awqn ilana izvlc ni a to lckunrcrc. Iwe Marku wqpq ninu awqn synqptiki to ku, fun
apccrc, o to nkan bi 90% iwe Marku ti a ze atunkq rc sinu iwe Matteu ati wipe o
to nkan bi 50% (idaji) iwe Marku ni a ri ninu iwe Luku, nigbati iwe Marku ni
ida qgbqn 30% eyi ti a ze atuntc rc ninu iwe Matteu ati Luku.
Idaji (50%) ohun to wa ninu iwe Matteu
ni o jq ti Marku, nigbati ida ogoji 40% iwe Luku jq ti Marku, bakanna iwe
ihinrere Matteu ati Luku ni csc igba (200) ti o jqra. Awqn to jqra ninu iwe Matteu
ati Luku jc awqn ikqni nipa Jesu Kristi pclu awqn ohun elo dic nipa alaye ijiya
Kristi. Ipa kcta awqn afijq yi ni o nii ze pclu itan iwaasu ati gbolohun qrq jc
apccrc ti o wqpq ti a le ri ninu awqn iwe wqnyi:
1. Matteu-9:1-2,
3-8
Marku-2:
1-6, 7-12
Luku
5:17-26
Ibeere
ti o tvle ni qrq nipa aawc gbigba.
2. Matteu
9:14-17
Marku-2:18-22
Luku
5:33-39
3. Matteu-9:18-26
Marku-5:21-39
Luku-8:41,
52-56
4. Matteu-8:26-34
Marku-1:1-28
Luku-8:26-39.
QNA
ABAYQ TI A ZE AGBEKALC RC LATI YANJU IZORO SYNQPTIKI (ERONGBA)
Orisi
qna abayq meji ni a ze agbekalc rc si izoro synqptiki;
1.
Erongba iwe ilewq meji
2.
Erongba iwe ilewq mcrin
ERONGBA
IWE ILEWQ
MEJI
Ni qdun 1835,
arakunrin kan ti a npe ni C. Lachman
ti o n rin ni oju qna kan naa, ohun ni o gbiyanju qna abayq to yatq, ti o mu
gba pe Marku ni cni akqkq ti o kqkq kqwe ninu awqn ihinrere synqptiki, ati wipe
nze ni awqn Matteu ati Luku lo iwe Marku lati kq ihinrere tiwqn.
ERONGBA IWE ILEWQ
MEJI

MK Q
MATT LK
ERONGBA IWE ILEWQ MCRIN
Itcsiwaju wa nipa atunze si erongba iwe ilewq yi lati qwq arakunrin
F.C.GRANT
ati arakunrin
B.H.STEETER ni qdun
1924 ati qdun 1957, ninu igbiyanju wqn lati fc erongba iwe ilewq meji yi loju,
awqn qjogbqn meji yi ze agbekalv erongba iwe ilewq mcrin (orisun ti o pq). Ni
afikun si Marku ati Q gcgc bi orisun erongba iwe ilewq mcrin ze agbekalc miran pe ki orisun kan wa ti a o
pe ni ‘M’ fun Matteu, ki orisun miran wa ti a o pe ni ‘L’ fun Luku, ki ‘Q’
o wa fun Marku,
ki orisun miran ti a o pe ni “MK”
tun wa fun Marku
bakanna.
Q
- Orisun
- Marku
M
- Orisun
- Matteu
L
- Orisun
- Luku
MK -
Orisun
– Marku
Olukuluku wqn ni wqn
ni orisun tiwqn ni cyq kqqkan.
Izoro synqptiki dide lati ibi
igbiyanju lati ze alaye ijqra gbogboogbo eyi to wa laarin Matteu, Marku ati Luku
nigba ti a ze akqsilc iyatq olukuluku wqn. Meji ninu awqn onkqwe iwe ihinrere
mcrccrin (Marku ati Luku), wqn kii ze cni ti izvlc ti wqn kq nipa rv zoju rv,
sibv, awqn ibeere kan wa nipa onkqwe meji to ku (Matteu, Johannu) Eleyi tumqsi
pe a ko le ro pe awqn afijq ati iyatq laarin ihinrere yi o wa lati inu iwoye
olukuluku onkqwe gcgcbi ogbifq fun Jesu ati izc iranzc rc. Awqn orisun miran
dabi cni pe wqn lqwq si bi a ti kq awqn ihinrere mcrccrin.

ERONGBA IWE ILEWQ MCRIN
1.





M 2. MK 3. Q 4. L



M 2. MK 3. Q 4. L
MATT LUKU
Ni nkan bi cgbcrun qdun meji schin (2,000yrs),
awqn qjqgbqn kan ni wqn ti fi ara wqn jin fun atize awari orisun na, bi o tilc
jc pe iye meji wa boya won o se azeyqri lori erongba wqn yi. Awqn ero ori kan
ni o tun su yq lati agbqn kan, akqkq ni awqn synqptiki fun ra wqn. Ekeji nipe
meji ninu awqn ihinrere synqptiki gbckcle ihinrere miran.
Titi di nkan bi
cgbcrun din igba tabi cgbesan tabi 1,800years, ijq gbagbq lati inu ero qkunrin
ti a npe ni Augustine, ti o wipe Matteu ni o kq ihinrere akqkq, Marku ni o ze
adakq Matteu, Luku si lo awqn meji lati kq iwe tirc.
Qpq
awqn qjqgbqn ni wqn gba bayi pe o kere ju meji paapa julq mcrin ni orisun ti o
wa lchin iwe ihinrere synqptiki. Akqkq ti o si ze Pataki ju ni ihinrere Marku,
kii ze iwe Matteu gcgcbi ijq ti kqkq gbagbq. Iwe Marku ni czc bi 666 (laika ori
kcrindinlogun czc kczan titi de ogun) eyi ti awqn qjqgbqn gba pe a ze afikun rc
lcyin ti wqn ti kq iwe na tan. Apapq awqn csc ti o to 606 ni o tun farahan ni
awqn qna kukuru ninu iwe ihinrere ti Matteu, ti o jc 1,071 vsv ti o to 350 lati
inu iwe Marku tun fi ara han ninu iwe ihinrere ti Luku ti o to 1,151 vsv.
Eleyi tumqsi pe, ju idaji iwe Matteu ati idakan ninu mcta iwe Luku ni
a kq lati inu ohun elo Marku. Csc mqkanlelqgbqn iwe Marku nikan ni ko farahan ninu iwe Matteu ati Luku. Qpq awqn akiyesi fihan
wa pe Marku ni orisun kii ze Matteu ati Luku.
Lakqkq, Matteu ati Luku wqn ko fohun sqkan ninu agbekalc ohun elo wqn
bi a ba fi wqn we iwe Marku. Nibi ti Matteu ati Luku ti tako awqn izclc kan
ti Marku gba ni tirc. Clvkeji, qpq ckunrcrc
qrq ninu iwe ihinrere Marku ni wqn gbe oju foo tabi ti wqn yq kuro ninu iwe
ihinrere Matteu
ati Luku. Jc ka ze afiwe wqn, Marku 4:1, Matteu 13:1-2, Luku 8:4.
Bi Marku ze kiyesi awqn igbe aye awqn qmq
cyin ni a yq kuro ninu iwe Matteu ati Luku, nitori qwq ti wqn fun wqn gcgcbi Aposteli. (Marku
6:52; 9:32). Marku sq awqn qrq yi nitoripe o ni igboya lati sq, nitori awqn iwe
ihinrere yoku ko sq boya nitori ki wqn le bu qla fun awqn qmq-cyin nitori ize
Pataki wqn gvgvbi Aposteli.
Marku tqka si ihuwa
si Jesu bi eniyan; Marku 14:34 jc ko di mimq fun wa pe Jesu ni ibanujc, zugbqn Matteu
ati Luku fi qrq yi pamq. Marku 8:12- Jesu kcdun gidigidi, Marku 10:13-14- Jesu
binu nitori iwa ti awqn qmq chin Rc hu lati di awqn qmqde lqwq.
Awqn qrq miran wa ti
awqn iwe yooku ti wqn gbe fuyc, fun apccrc, ipa tabi agbara ti Jesu ni lati ze
awqn isc kan ni a yq kuro lati qwq wqn. Marku 6:6, Matteu 13:58, Luku 4:23. Ni
abala miran Matteu ati Luku ninu izclc miran tan imqlc si azeyqri Jesu nipa ikaanu.
Marku 1:32-34, Matteu 8:16. Bi a ba ro pe Matteu ati Luku ze adakq iwe Marku ni,
yoo rq wa lqrun lati ze alaye wqn, zugbqn yi o nira bi a ko ba gba bcc.
Q GEGE BI
ORISUN
Nigbati a ze akiyesi awqn ohun elo ninu
iwe Matteu ati Luku, awqn onkawe ze awari rc
pe o ju igba czc (200 vsv) ti ko farahan ninu iwe Marku rara. Awqn ohun elo yi ti o kun
fun ikqni Jesu, ti a si le pin si isqri mcrin.
1. Jesu ati Johannu Baptisi (onitvbqmi)
2. Jesu ati awqn qmq-chin rc
3. Jesu ati awqn alatako rv
4. Jesu ati qjq iwaju
Awqn qjqgbqn gba pe awqn ohun elo yi gbqdq jc eyiti o wa
lati orisun ti o han si Matteu ati Luku nikan, zugbqn fun ere idi idanimq,
orisun yi ni a npe orukq rc ni (Q)
eyiti o wa lati inu ede (Germany) ti a
npe ni
“Quelle”, eyiti o tumq si ‘orisun’ tabi ‘ojulowo’.
Iwe ilewq ti a pe ni “Q”
yi ni o dabi imq ori niwon
igbati akori cda, Ozeeze,
amoza, pe iwe ilewq kan, eyi ti o ni awqn qrq Jesu ninu ti o si wa ni ibamu
pclu “Q”
ni
awqn ijq akqkq ri. Awqn baba ijq bii, Papias, ti wqn kqwe ni 130AD ze akqsilc
rc pe Matteu gba awqn qrq izipaya kan ni ede Heberu (Oracles) o si tumq rc bi o ti yee. A ko le sq
boya iwe izipaya ti o gba yi ni iwe ihinrere ti Matteu, zugbon o zeeze ki o duro fun
orisun kan ti a lo fun iwe ihinrere Matteu ati Luku.
Awqn qrq Jesu ni wqn gbe l’arugc pupq ninu ijq akqkq, paapa
awqn itoni lori awqn azczc gbagbq, o si zee ze ki o jc pe, vsv igba (200 vsv)
ti Matteu ati Luku ni, ti o jqra, ni o duro fun orisun kan ti a ze akojqpq rv
lati qwq Matteu, eyi ti o han si Papias gcgcbi iwe isipaya (oracle)

IWADI AGBELCRQ
Lchin ogun agbaye akqkq, iwadi titun nipa awqn ihinrere bcrc
ni ilu Germany. Ilepa wqn ni lati mq aziri awqn alakqsilc (Marku, Q, ati L) ki wqn si ze iwadi qna ti wqn gba fi
ihinrere zqwq nipa qrq cnu lati akoko ti o wa larin iku Jesu ni
(AD 30) titi di akoko ti Paulu kq iwe ni (AD 50).
Ile iwe ironu yi sinmi le qpqlqpq awqn
arojinlc:
1. Wipe itan ti a fi lelc nipa Jesu ni o
pada di eyi ti a pin si awqn isqri bi; awqn itan iyanu, awqn owe, awqn gbolohun
qrq agbara, Marku
2:27, Mark3:35, ati oniruuru awqn qrq ti Jesu sq. Matteu 6:19-34, paapa julq
akqsilc iku Jesu.
2. Erongba miran nipa iwadi agbelvrq sq
wipe awqn ijq akqkq ze iranti, wqn si ze atunze, wqn si fi awqn abala ikqni
Jesu ati izv iranzc rc zqwq si awqn vlomiran eyi ti o wa ni ibamu pclu ipo ti
wqn wa.
Eleyi tumqsi pe, ni afikun sisq nipa
Jesu, ihinrere sq fun wa nipa ijq akqkq ti o fi itan Jesu sqwq si awqn
clomiran. Eleyi tumqsi pe awqn ijq akqkq ko ri Jesu bi opomulero aworan igba
atijq lasan, zugbqn bi Oluwa ti o wa laye titi di isinsinyi.
Arojinlc keji yi ni a fi idi rc mulc ninu iwe ihinrere ti
Johannu nitori ti o ran wa leti awqn ohun manigbagbe ti a fi idi rc mulc nipa
Jesu lati pasv Cmi-Mimq (John 14:26). A ko sq pe awqn ijq akqkq kan gbe itan
kalc, ati pe ki wqn kan waasu nipa Jesu cni ti o kan jc aworan ti a nwoye rv zugbqn
o tumq si pe, ijq akqkq pa oye nipa Jesu mq nigbti awqn miran ko naani cni ti
Jesu nze, awqn izclc ati awqn qrq Oluwa ni oze Pataki ni oju ijq akqkq ju awqn
miran lq. Bi o tilc jc wipe awqn iwadi mcrin si wa ni ipo qmq qwq, zugbqn o ti
ran wa lqwq lati mo riri ipa ti ijq akqkq ko nipa idasilc ihinrere. O zeeze ki
a mq boya ijq akqkq yvpvrc itan Jesu tabi wqn pa ohun ti wqn gbagbq nipa itan
Jesu mq. Ze bcc ni?
Majcmu titun fi
awqn ohun kan han wa eyi ti o yc ki a fi kiyesara nipa bi a o ze sqrq nipa ijq
akqkq. Awqn ijq akqkq gbiyanju lati pa vri Oluwa mq nitori qpq awqn ti izvlv yi
zoju wqn ati dic lara awqn Aposteli zi wa laye nigbati a kq iwe ihinrere jade, awqn
ti izclc yi zoju wqn ni wqn kin qrq yi lchin ti wqn si dabobo ihinrere kuro
lqwq idibajv.
Siwaju si, a mq pe ijq akqkq dojukq inunibini nigbati wqn
bvvrv si ni waasu ihinrere lqdq awqn keferi. Qkan lara inunibini ti wqn doju kq
ni gbigba awqn keferi sinu ijq ati paapa qrq ikqla, zugbqn irufc qrq bcc ni a
darukq rv ninu ihinrere (Matteu 8:10).
Lakotan, awqn qrq ati awqn gbolohun ti o nda ni l’qkan ru,
zugbqn ti o ze Pataki si ijq akqkq ni o wa ninu awqn ihinrere, bi qrq nipa awqn
qmqde. Marku 10:13-16, tabi awqn izvlc ti a n ranti to n banilqkan jc bi igba
ti Peteru sc Jesu (Peter’s denyer) marku 14:66-68, awqn wqnyi tqkasi pe ijo
akqkq ni ipinu lati da aabo bo aza wqn tiwqn gba, ju ki wqn kan sq aworan wqn
di titun.
IWADI ALATUNZE
Lati igba ogun agbaye clckeji ni awqn qjqgbqn ti se iwadi nipa ihinrere
ni agbegbe miran, wqn tcjumq ojuze awqn onkqwe ihinrere gcgc bi alatunto si
awqn ohun elo ti wqn gba lqwq ijq akqkq. Qrq ti a pe ni iwadi atunto ni o wa
lati inu ede Germany ti a npe ni ‘Redaction’ti o tumq si ‘Editing’ ti o tumqsi ‘atunto’ Orisun
yo’wu ki onkqwe jogun, awqn alatunto yi ti fihan wa pe awqn onkqwe ihinrere ju
onkqwe akqsilc itan lo dabi clvri awqn ohun elo ti wqn fi zqwq.
Olukuluku wqn ni wqn jc okun lara eyi
ti o so wa pq mq Jesu. Olukuluku wqn ni o fi
aworan Jesu han ni qna to yatq, nitoripe olukuluku wqn kqwe si awqn olugbq ti o yatq, ti wqn si tvnu
mq abala to yatq nipa igbe aye Jesu.
Fun Marku,
Jesu jc iranzv to n da ze akoso ti o si ze afihan jijc qmq Qlorun Rc lori
agbelebu. Ohun ti Matteu tcjumq ni lati fi Jesu han gcgc bi olukq ni ti o tobi
ju Mose lq, ti o si ntcsiwaju lati wa pclu
awqn qmq vhin Rc. Fun Luku Jesu ni okuta Pataki ninu itan igbala ti a bcrc pclu
Isreali, ti a mu ze ninu Jesu ti a si sq di mimq fun ijq.
Onkqwe ihinrere kcrin ze afihan aditu jijc Qlqrun ninu
eniyan cni ti o mu iye wa sinu aye nipa gbigbckcle (Johannu 1:14).
AWQN
SYNQPTIKI ATI
IHINRERE
JOHANNU
Yio jc azize pe Johannu yatq si awqn
ihinrere yoku ati wipe ko nilo ki a ze agbeycwo rv pclu wqn. Gbogbo iwe
ihinrere mcrccrin ni o ze afihan Jesu lati pasc abala izvlc kqkan ninu aye Rc.
Leke gbogbo rc ni iku ati ajinde Rc. Zugbqn Johannu fi Jesu han lqna to yatq ati
lai gbckcle orisun iranwq lati ibomiran.
Ninu synqptiki izc iranzv Jesu ko to
qdun kan, o si waye paapa ni Galili. Ninu iwe Johannu, izc iranzv Jesu gbooro
ju bi qdun mcta lq ti o si waye lqpq igba ni Judea. Synqptiki fi Jesu han gcgc
bi qmq eniyan ti o ni ize ti o nfi aworan qrq han awqn olugbq rc. Amqza, Johannu
ko fi aworan han, zugbqn o sq nipa aye Jesu ati ikqni ti o wa taara, ti o si kqni
nipa ara rc. Ninu synqptiki, Jesu kqni nipasv owe, awqn owe yi fvrv to qgqta
lapapq, zugbqn ninu ihinrere ti Johanu, ko si owe rara.
Ninu synqptiki, Jesu kqni nipa ijqba
Olorun, ti o si jc wipe ninu ihinrere ti Johanu, o kqni nipa ara Rc. Ninu
synqptiki, Jesu bcbc pe ki wqn maze polongo ohun lati qwq awqn ti wqn ri izc
iyanu rc, zugbqn ninu Johannu awqn izc iyanu lo fi Jesu han ati izc iranzc rc.
A le ma ni oye to kun nipa bi awqn
ihinrere ze bcrc ati awqn orisun ti olukuluku lo fun awqn iwe wqn, zugbqn
ipenija ti o ju ni ki a wa aditu nipa ihinrere yi, ki a kq bi a ti n mq riri bi
olukuluku onkqwe ze ze afihan Jesu ni qna to yatq, ki a si ma dagba ninu ifv
ati ifara cni jin fun-un.
AFIHAN: Ihinrere ti Matteu zq fun wa nipa
irohin ayq pe Jesu ni olugbala ti a seleri rc vni nipasc qna ti Qlqrun gba mu
awqn ileri Rc zc ti o ti sq ninu majcmu laelae. Iroyin ayq yi kii se fun awqn eniyan
Juu nikan, laarin awqn ti a ti bi Jesu, to dagba, ti o si ngbe igbe aye rv ni arin wqn, zugbqn fun gbogbo
agbaye. Iwe Matteu
ni a to leto daradara.
O bcrc pclu ibi Jesu, o se alaye
iribqmi Rv ati idanwo Rc, lchin naa ni o sq nipa izc iranzc iwaasu rc, ikqni
ati izc iranzc imularada ni Galili. Lchin eyi, ihirere yi ze akqsile irin ajo
Jesu, lati Galili lq si Jerusalvmu ati awqn izvlv qsv Jesu ti o gbcyin, eyi ti
o wq inu kikan mq agbelebu rv ati ajinde Re.
Ihinrere Matteu ze afihan Jesu bi olukq
nla, vni ti o ni asc lati tumq ofin Qlqrun ti o si tun nkoni nipa ijqba Qlqrun,
qpq awqn ikqni rv ni a to ni isqri- isqri gcgc bi izvlc wqn ti a si ko wqn jq
si ipele marun.
1. Iwaasu ori-oke, eyi ti o ni se pclu ihuwasi,
awqn ojuse, awqn anfani ati ayanmq cni ti o bajc qmq ijqba qrun.
2.
Awqn itqni fun awqn qmq vhin mejila fun izv
iranzv wqn (Matteu
10)
3.
Awqn owe nipa ijqba qrun (Matteu 13)
4.
Ikqni lori jijv qmq vhin (Matteu 18)
5.
Ikqni nipa opin akoko yi ati wiwa ijqba qrun (Matteu 24,25)
Ihinrere ti Matteu ni ihinrere ti ijq fvran ju titi di akoko Irenaeus.
Ihinrere Matteu
farahan gcgcbi eyi ti o rqrun lati ye ni gege bi iwe ti a kq si awqn Juu
kristcni ni akoko ti o tvle qdun ti a wo Jerusalem palc ni A.D 70, ni akoko yi
ni ijq ati Synagqgu nrin lqtqqtq ti awqn Juu kristcni si ndoju kq awqn wahala,
nipa qna ti wqn le gba mu qrq naa ni irufc akoko yi.
CNI TI O KQ
IWE
NAA
Bi o tilc jcpe itan fi ihinrere akqkq
sqri Matteu, zugbqn izc inu rv jc eyiti a ko mq eniti o ni. Orukq ti a pe ni “Matteu” yi ko farahan ninu iwe rc lati
se apejuwe vni ti o kqq. Matteu, agbowo-ode, cni ti o pada di qkan ninu awqn
Aposteli Jesu mejila (Matteu 9:9). Orukq Matteu farahan ni ipo keje ninu akqsilc
awqn aposteli mejeji. (Matt 3:18, Luku 6:15). Orukq rc farahan ni ipo kcjq ninu awqn
iwe meji miran (Matteu 10:3; Ize awqn Aposteli
1:13).
Ni ede Heberu, orukq Matteu tumqsi “Ma-thue” ti o tumq si cbun Qlqrun tabi cbun
Jehofa (Gift of God) zugbqn a mq lati inu owo rc pe, o feran vbun awqn vlomiran
bakanna. O jc agbowo ode (Matteu 9:9-11) cni ti o nzizv ni agbegbe kapanamu
labc azc Hcrqdu Antipasi. Ni akoko Jesu, wqn ma ngba owo ile ati opo taara lati
qwq awqn osisc ijqba Romu, sugbqn awqn owo ori lori awqn cru ti wqn ba ko wqle,
ni wqn fa le awqn agbowo ode ti ijqba ibilc lqwq. Matteu jc qkan ninu awqn
eniyan ti o nze iru izc isin yi. Awqn Juu korira awqn agbowo ode, kii ze nitori
iwa ibaje wqn nikan, zugbqn nitori wqn nzizc papq pclu awqn ara Romu cni cgan.
Awqn agbowo ode ni a to papq pclu awon apaniyan ati awqn adigunjale, a si fi aaye
gba Juu lati parq fun wqn ti o ba zeeze.
Ihuwa si ti a ri ninu ihinrere yi jqra. A zeto agbowo ode pq mq alagbere ninu iwe (Matteu 21:31). A to awqn agbowo ode
pclu awqn keferi (Matteu 18:17) ati lqpq igba a to wqn papq pclu awqn clcsc (Matteu
9:10). Wqn jc ohun ikqsc fun awqn Juu, fun eto qrq aje ati izv wqn lawujq gcgc
bi awqn advtc ze di cni ikqsilc nitori aimq wqn, awqn mejeji ni a yq kuro laarin
awqn eniyan Qlqrun.
AKOKO ATI IBI TI A TI KQ IWE NAA
Ko si vri to daju pe a tete kq iwe Matteu
siwaju awqn iyoku rc, zugbqn a mq pe iwe Marku ni a ti kq siwaju rc ni qdun A.D
65 or 70. Ibi ti a ti ze akojqpq ati kikq iwe Matteu ni a ko mq, o si zoro lati
mq. Onkqwe na kq iwe yi si awqn eniyan ti o nsq ede Giriki ninu eyi ti ari awqn
Juu ati awqn keferi, awon ara Palestini, papa julq awqn ara Galili ni a ko le fqwq
rq schin. Niwon igbati clcri to ti Matteu lchin jc Ignatius, nitorina Antioku
ati agbegbe Siria ni o jc ibi ti a ti kq iwe naa, bi o tilc jcpe Phoenisia tabi
kesaria ni qpq gbagbq pe a ti kq.

IHINRERE
TI MARKU
AFIHAN: Ihinrere ti Marku bcrc pclu
gbolohun qrq yi “Ihinrere nipa Jesu Kristi qmq Qlqrun”. A ze afihan Jesu gcgc bi cni ti o ni ize ati
azv. A ri azc Rc ninu ikqni Rc, ninu agbara Rv, lori awqn cmi ezu ati ninu
didari czc ji awqn eniyan. Jesu sq nipa ara Rv bi qmq eniyan cni ti o wa lati
fi ara Rv silc ki o le sq awqn eniyan di ominira kuro lqwq csc. Marku ze afihan
Jesu ati awqn itan ti o ni ze pclu Jesu ni qna taara ati qna to ni agbara, pclu
ti tcnu mq ohun ti Jesu ze, ju awqn qrq rc ati ikqni Rc lq. Lchin ti oti sqrq
kukuru nipa Johannu onitcbqmi ati baptisi ati idanwo Jesu, loju kanna ni onkqwe
yi yara sq nipa izc iranzc Jesu ti imularada ati ikqni. Bi akoko ti n tcsiwaju,
ni awqn qmq chin Rc pada ni oye nipa Rc daradara, zugbqn awqn alatako Jesu wa nburu
si. Awqn ori ti o gbcyin iwe Marku sq nipa awqn izclc qsc to kchin igbe aye
Jesu lori ilc aye, paapa ki a to kan mq agbelebu ati ajinde rc.
Marku ni ihinrere akqkq ti a kq ze
akojqpq rc, eyi ti a yiriwo ti awqn onkqwe synqptiki yoku si lo lati kq iwe
tiwqn gcgcbi itan ze sq fun wa. A kq ni ilc Romu lati qwq Johannu ti apele rc
njc Marku ni opin qdun A.D. 60. Johannu Marku jc ongbifq fun Peteru ati pe
lchin iku Peteru ni a ze akqsilc iwe ihinrere yi ni agbegbe Itali. Johannu ti
apele rc njc Marku, cni ti o jc ongbifq ni o ni anfani lati ze akqsilc ni
ckunrcrc ohun gbogbo ti o ranti ati awqn ohun ti Oluwa sq ati eyi ti o ze.
Marku ko le sq ohun gbogbo ti Jesu ze ati eyi ti o sq tan. Nitori oun ko si
ninu awqn qmq chin, bc ko si gbq ikqni Jesu, zugbqn lchin q rchin o ni oye si
bi o ti ntcle Peteru cni ti o nze ikqni qrq Qlqrun gcgc bi akoko ba ti bere
fun. Marku a ma se akqsilc awqn iwaasu eyi ti Peteru ba ti n wa.

CNI TI O KQ IWE MARKU
Yio jc ohun ti o dara ki a bcrc pclu zize agbeycwo itan pclu
awqn iyiriwo ti yi o fi idi erongba wa mulc pe Johannu ti apele rc njc Marku ni
o kq ihinrere yi. Ko si ohun kan ti yo di wa lqwq ninu rc lati gba pe a kq
ihinrere yi lati qwq Johannu ti a npe ni Marku, alaba zizc pq pclu Peteru.
Bakanna, awqn ibeere kan jcyq boya oun ni qkunrin ti a darukq rc ninu awqn iwe
mimq yi (Ise awqn aposteli 12:12-25; 3:13; 16:36-39; Kolo. 4:10; 2Tim 4:11;
Filemqni 24)
AKOKO ATI IBI TI A TI KQ
IWE NAA
Otitq pe Marku se alaye aza awqn Juu
ati pe o tu awqn qrq kan ni ede awon ara Aramaic, eleyi jv itqka si pe o kq iwe na fun
awqn keferi. Itan fi ye wa pe ilu Romu ni a ti kq iwe ihinrere Marku. Marku.15:21
le ni awqn qrq atilcyin ninu ti o fi idi rc mulc pe ilu Romu ni orisun ibi ti o
ti kq iwe Marku.
IHINRERE
TI LUKU
AFIHAN: Ihinrere ti Luku fi Jesu han
gcgcbi olugbala Isreali ti a ze ileri rc ati olugbala gbogbo iran eniyan. Luku ze
akqsilc rc pe, a pe Jesu lati qwq cmi mimq lati mu iroyin ayq wa fun awqn
talaka, ihinrere yi si kun fun ibakcdun fun awqn eniyan pclu gbogbo orizi aini
wqn. Qrq ayq pq ninu iwe Luku, paapa ninu awqn ori ti o zi iwe naa, ninu eyi ti
o ti kede wiwa Jesu ati ipari iwe naa,
nigbati Jesu goke re qrun. Itan idagba ati itankalc igbagbq kristicni lchin
igoke re qrun Jesu, ni a ti qwq onkqwe kan na kq silc ninu iwe Ise awqn Aposteli.
Awqn ohun elo kan wa ti a ri ninu iwe ihinrere Luku nikan, gcgcbi awqn itan nipa
orin awqn Angcli ati ibcwo awqn Olusq-aguntan ni igba ti a bi Jesu, Jesu gcgcbi qdqmqde ninu tcmpili ati owe nipa ara
Samaria rere ati ti qmq qkunrin to sqnu. Ninu gbogbo ihinrere yi, atvnumq qrq
adura daradara, atvnumq qrq vmi mimq, ojuse obinrin ninu izc iranzc Jesu ati
idariji czc Qlqrun.
Ihinrere ti Luku ati iwe ize awqn Aposteli ni a ti qwq
onkqwe kan na kq, eyi ti o si jc iwe orisi meji ninu isc kan naa. Isc naa kqja
eyi ti a le tako. Qrq akqsq ninu ihinrere Luku ntqka si awqn qrq ti o wa ninu
iwe Ize awqn Aposteli, ati wipe awqn akqsq ninu Ize awqn Aposteli jc eyiti o
faramq ohun ti o wa ninu iwe ihinrere naa. Iwe mejeeji yi ni a fi jin fun
Tiofilu. Ibi ti ihinrere Luku pari si ni o gbe vnu le ibcrc iwe Ize awqn Aposteli. Awqn iwe mejeeji sqkan
pupq ni isqwq kqwe, gbolohun qrq, awqn iwa ti o nru ni lqkan soke ati ilana
izqkan.
ENI
TI O KQ IWE NAA
Gcgcbi awqn ihinrere mvta ti o ku, a ko
mq cni ti o kq iwe Luku. Sugbqn itan sq wipe ihinrere Luku ati Ize awqn Aposteli
ni a ti qwq Luku kq silc, cni ti o jc onizegun oyinbo ati alabazizc papq pclu
Paulu. Lati inu Majcmu Titun, a le ze awari awqn qrq afi toni leti yi nipa Luku
(Col 4:14) Filemqni 24, 2Tim 4:11
1.
Luku jc keferi: [qrq yi da lori kol 4:11 nibi
ti a ko ti darukq Luku mq awqn vni ikqla ti wqn jv alaba sisc papq pelu Paulu
ninu qgba cwqn rc].
2.
Luku jc Dokita onimq isegun oyinbo.
3.
Luku jv alabazizc papq pclu Paulu.
Bi a ba le fidi koko mcta yi mulc pelu
awqn ohun ti a kq sinu Luku ati ize awqn Aposteli eleyi yio fi idi rc mulc pe Luku
ni cni ti o kq ihinrere yi nitoripe qrq akqsq ihinrere Luku tqka siipe onkqwe
yi jc Helleni.

AKOKO ATI IBI TI A TI KQ IWE NAA
1.
Iwe Luku yio wa laarin iwe Marku ati ize awqn Aposteli.
Eleyi tumq sipe akoko ti a kq iwe ihinrere Luku ni ze pclu akoko ti a kq Marku
ati ize awqn Aposteli. Awqn qjqgbqn sq wipe a kq ihinrere Luku ni qdun A.D
65-68. Marku si jc orisun akqkq fun ihinrere Luku, nitori naa akoko ti a kq
ihinrere Luku yo jc bi qdun A.D 70.
EREDI TI A FI KQ IWE LUKU
Awqn aba wqnyi ni a le sq nipa eredi
eyi ti o ru qkan Luku soke lati kq iwe ihinrere Luku ati Ize awqn Aposteli.
Nigbati Matteu nkowe lati inu imqlc awqn izvlc ti o nzclc nigba ti a nni ijq
lara, wqn si ti de opin ipinya laarin csin Juu ati csin kristeni. Luku paapa
nkqwe larin akoko naa ti iyapa laarin csin Kristicni ati csin awon Juu ti di
otitq.
Luku nkqwe lati fi idi itcsiwaju laarin csin
awqn Kristcni ati itan irapada awqn Juu mulc ati lati ze akawe bi csin awqn
Kristicni, eyiti o bcrc, gcgcbi ara abala vsin awqn Juu se pada di csin miran
ti o yatq.
Wqn da gcgcbi aba pe, Luku nkqwe lati
fi idi rc mulc pe, vsin awqn Kristieni kii ze ohun ti o ndcruba azc ozelu ninu
ijqba Romu. Amqza, awqn csc qrq Qlqrun ti o wulo ninu Ize awqn Aposteli ni o
fun wa ni awqn itumq miran ati wipe awqn qrq idaniloju ti a kiyesi ninu
ihinrere yi, farahan bakanna ninu ihinrere miran.
No comments:
Post a Comment