THE CHURCH
Introduction:
The word church was first heard in the book of Matthew, but the church came
into existence on the day of Pentecost. Matt. 16:18
Definition. TANI A LE PE NI IJO?
1. Ijo ki i se ogiri ile ijosin, bikose
apejopo awon eni irapada. Rom. 16:5
2. Ijo je ikojopo awon ti a pe jade lati
inu ayee.
3. Ijo je awujo ti o wa laaye, sugbon
laaarin agbegbe ajoji. Jn. 15:17-19
ISE IRANSE ONIPELE
META TI IJO
1. Lati fi ogo fun Olorun, lati josin si
ninu Emi ati otito. Jn. 4:23-24
2. Lati ko ni leko, lati se won peye ati
lati fi ese won mule sinu ife Olorun. Eph. 4:11-16, Matt. 28:19-20
3. Lati waasu ihinrere ijoba Olorun, ati
lati mu elese pada wa sodo Olorun. Mk. 16:15-16
IRETI OLORUN LORI IJO
RE
1. ----------Rom. 12:1-2
2. ----------Matt. 5:48
3. ----------Eph. 5:1-2
IPO AWON IJO NI
IKEYIN AYE (Rev 2&3)
IJO EFESU (Rev 2:2-6)
1. Didan awon ke Aposteli wo
2. Ifarada iya nitori oruko Oluwa
3. Fifi ife isiwaju sile
4. Kikorira ise awon Nikolaitani
IJO SMIRNA (Rev. 2:9)
1. Ijo alairiwisi (o ni iponju ati aini)
iponju lo so elomiran di elese
IJO
PAGAMU (Rev 2:13-15)
1. O n gbe ibi ti ite satani wa, o si di
igbagbo mu
2. Iwo ni awon to eko Balamu mu.
3. O ni awon to gba eko Nikolaitan.
IJO TIA TIRA (Rev. 2:20)
1. Fifi aye gba Jesebeli
IJO
SARDI (Rev 3:1-4)
1. O ni oruko pe owa laaye, sugbon o ku.
2. Emi ko ri ise re ni pipe niwaju
Olorun
3. O ni awon die ti ko fi aso won yi
eeri
IJO
FILADELFIA (Rev 3:8)
1. Ijo ti ko ni agbara pupo, sugbon won
npa oro Olorun mo
IJO
LAODIKEA (Rev 3:15-17,20)
1. Ijo ko gbona ko tutu
2. Ijo ti o npe ara re ni ohun ti ko je
3. Ijo ti o ti Jesu sita.
AGBARA
TI IJO NI (Matt 20:23)
1. Agbara lati dari ese jin ni
2. Agbara lati da ese duro
No comments:
Post a Comment