AWON
ILANA IKONI ILE EKO
OJO ISINMI TI O
MUNA DOKO
AFIHAN:
Bi ba fe je olotito si ara wa a o gba wipe opo ninu awon ijo
wa loni ni ko dagba rara, lara oun ti se okunfa re naa ni ase awari de ikuna
tabi aijagaara ti agbon ile eko ojo isimi. Bi ida aadorin awon ijo wa loni ni
won nse eko ojo isimi, sugbon ipa won ni ko to nkan ninu ara Kristi (church or
body of Christ). Nipa wiwo nkan tabi bi nkan se nlo ni iran wa yi, o dabi pe
erongba okan Olorun tofi fi agbon ile eko ojo isimi lele ninu ijo re ni o ti
fori sonpo, ohun to si fa naa ni owo ere henhe ti afi mu (poor war of handling
it).
Asiri ti o han gbangba ni wipe awon oluko ile eko ojo isimi
sumo awon omi ijo ju oluso aguntan lo. Ise Oluso-aguntan kibati fuye to ba se
wipe awon oluko ile eko ojo isimi di alafo to ye ki won o di. Eredi eyi ni wipe
awon ni o ye ki o fi ipile eko igbagbo Kristieni lele fun awon omo ijo. Nitori
naa oni lati gba wipe ohunkohun to ba sele ninu ijo loni iwo gege bi oluko ile
eko ojo isimi ni ao bi leere, nitori iwo ni ofi ipile irin ajo Kristieni won
lele.
Bi aba ni olote ninu omo ijo tabi alagbere, eni to nrin
segesege, ati ahun. etc. agbudo mo wipe Olorun yio se awari eyi pada si odo re
gegebi oluko won. Ohunkohun ti aba fe ki ijo ki o da owa lowo tabi ni ikawo
awon oluko ile eko ojo isimi.
Bi oruko ti se ri, ile eko ni ti ama nlo ni ojo isimi
nipataki ni aaro nigbati awon eniyan bawa niwaju Olorun.
Ilana ile eko ojo isimi ti o munadoko nise pelu ipa ti eko
naa yio ni.
1. IMUNA DOKO:
Eyi ni agbara lati gbe jade esi ti eniyan nreti tabi so oju abe niko. Otumo si
wipe oni afoju sun kan to n reti. Ise awon Aposteli.2:37-38.
2. IPEYE: Eyi ni
iye ifarabale, okun, mimo se sisetan tabi igbaradi ti afi sinu ise kan ni yio
so abajade re. Matt.7:28-29
ORISUN
ILE EKO OJO ISIMI
Ile eko ojo isimi ni ada sile lati owo okunrin ti ape ni “ROBERT RAIKES” Akoroyin kan ti o ngbe
ni ilu oba (England). Ohun naa ni o bere eto ile eko ojo isimi ni “July 1780
A.D”.
Eto yi bere ninu ile obinrin kan ti a npe ni “MERIED TH” pelu
awon omo kekere pelu erongba lati ma ko won ni awon eko imo isiro (mathematics)
ati bi won ti se le mo ko ati mo ka. Okunrin (ROBERT RAIKES) yi se ifilo lati
ojule de ojule osi ko awon omo wewe jo fun eko. O npese ounje, aso osi nboju
towon, o tun ko won ni oro Olorun.nitori Oluwa wa pelu re. O si mu erongba re
se.

IGAGBASOKE
ILE EKO OJO ISIMI
Laarin odun 1800 ati 1900, ile eko ojo isimi ti dagba de
ipele ti ko se fowo ro seyin ti o si di agbon pataki ninu eto isin ijo nigba ti
o di mimo idi ti awon omo wewe fi nilo lati ko ni eko Kristieni ju ti eko ti
awujo lo. Deut.31:12-13.
Ni odun 1881 o fere je gbagbo awon ijo agbegbe ni o tewogba
eto ile eko ojo isimi. O dagba de ipele ti awon agba fi tewogba ti o si di
itewogba ni ibi awon ipade nlanla.
AWON
ENIYAN TI O TEWOGBA LATI ODO ROBERT RAIKES
A. Oludasile ijo methodist (o pase fun
gbogbo eka ijo re lati tewogba lesekese)
B. Oludasile ti Ijo Apostolic Faith
(titi o fi tan de orile ede Nigeria).
C. Assemblies of God Church (ni gbogbo
aye)
D. Bayi o ti di ilana eto gbogbo ile
ijosin
IDASILE
ATI ISAKOSO ILE-EKO OJO ISIMI
Ile eko ojo isimi ti o bere pelu awon omo wewe ti dagba de
ipele ti awon agba tewogba ti won si nlo. Awon ilana ati isakoso ni agbodo se
pelu ogbon Olorun. Iye awon akeeko gbodo bere lati mefa si mewa ati oluko meji.
AWON
OSISE N ILE-EKO OJO ISIMI
A. Olusakoso (co-ordinator)
B. Oluko (Teachers)
C. Olukowe ti kilasi
IDI
PATAKI ILE-EKO OJO ISIMI
a. Lati mu elese wa sodo Oluwa.
b. Lati mu isoji ti a nreti wa.
c. Lati fi onigbagbo mule ninu igbagbo
d. Lati mu ki awon ilana ijo rorun
e. Lati ko eko to ba Bibeli mu.
f. Lati daado bo aworan ijo ati lati pa
eri Kristi ati ti ijo mo.
g. Lati mu awon asese gbagbo ati awon
oju tuntun tesiwaju ninu ijo ati ara Kristi
h.
Lati mura awon onigbagbo sile fun ise ijo ati fun ise iranse.
Lati mura awon onigbagbo sile fun ise ijo ati fun ise iranse.
IWASU
ATI KIKO ILE-EKO OJO ISIMI
Iwaasu yato si ikoni, bo ti e je wipe won jo ara won sugbon o
ma nwa ni ona ototo.
IWAASU
ATI IKONI ILE EKO OJO ISIMI
Bi aba farabale wo akori yi, a o ri wipe ikan rorun ju ekeji
lo.
1. Iwaasu nwa lati okan oniwaasu nikan,
oun nikan ni o mo ohun ti o fe waasu.
2. Oniwaasu nikan lo ma nsoro ni opo
igba.
3. Oniwaasu ni ase ti enikeni ko gbudo bileere
oro tabi tako toba nwaasu lowo.
4.
Akoko iwaasu ma nkere si ti ikoni lo.
ISE
IRANSE OLUKO
Oro Greeki ti alo fun ise iranse ikoni ni “DIDASKO”. Gbongbo oro naa tumosi
kikoni ati fifi ase fun ni. Ona ati se alaye nkan. Nipase eyi imo tabi eko ni a
nfi sinu elomiran.
Ase Kristi ti o gaju fun awon omo eyin re ki o to pada lo si orun
ni pe ki won so opolopo di omo leyin ati lati ma ko won lati ma kiyesi ohun
gbogbo ti Jesu ti pa lase (Matt.28:18-20) nitori iru ise ati ilana ti ati fifun
oluko, nitori naa:
1. Oluko ko gbudo duro lati ma keko.
Rom.2:21
2. Oluko gbodo mo oro Olorun. Mark.12:24
3. Oluko gbodo ma koni pelu apeere rere.
Jn.13:13-14.
4. Oluko ni lati ma kiyesi oro re.
Matt.22:15.
5. Oluko gbudo ma lakaka lati mu awon miran
wa si ipele ti ohun wa ati jube lo. Matt.10:24-25.
6. Ere Oluko ti o ga julo ni lati ri
wipe aye awon eniyan nyi pada nipa oro Olorun.
Ni ipari. Gbogbo oluko ile eko ojo isimi ni
agba ni imoran lati mase waasu ninu kilasi won sugbon ki won koni nipa fifi aye
gba:
1. Awon akeko lati dasi eko ti won nko.
2. Lilo ohun ti ose fowokan bi apeere.
3. Riran won lowo lati ko awon ese Bibeli
kan sori ati awon to se koko.
4. Mimu ki iwe ikoni ti ile eko ojo
isimi wa ni arowo to.
5. Fun won ni aaye lati beere ibeere bi
eko ba nlo lowo ati leyin eko.
6. Pe ipe si iwaju nigba ti o bati fenu
ba awon koko oro kan ninu ikoni.
AGBARA
OLUKO ILE EKO OJO ISIMI
Olorun fun awon oluko ni awon agbara kan ninu re ni eyi:
1. Agbara lati gbin irugbin
2. Agbara lati kun ojulowo aworan Jesu
ati ti ijo
3. Agbara lati fidi eni mule sinu ara
Kristi
4. Agbara lati ni won fun Jesu Kristi
5. Agbara lati so tabi pinnu ojo iwaju
ijo ati ara Kristi.

OGBON
IKONI NINU ILE EKO OJO ISIMI
Ni abe akori kekere yi a o se ageyewo awon nkan wonyi:
IBARADI
FUN EKO ILE EKO OJO ISIMI
1. Akoko ti o po ati ojo pato agbodo wa
fun ayewo eko ti afe ko.
2. Oluko ti ko ba wa fun ayewo ko gbodo
koni, beeni ti oba ti ndi lemolemo ibawi gbodo telee.
3. Iwe ikoni ni ati gbodo pese sile
saaju akoko atunyewo eko ki osi ti te awon oluko lowo.
4. Atun gbodo ni akosile awon akeko ti o
wa ile-eko ti a se gbeyin
5. Gbogbo awon osise ile eko ojo isinmi
gbodo wa si ibi imuresile fun eko bi apeere: oluko ewe, awako, asona, ati awon
miran.
PIPIN
YARA IKEKO
Ohun ti nse agbelewon irufe akeko ti yio wa ni yara ikeko ni
wonyi sugbon ko duro lori eyi nikan.
1. Ojo ori
2. Ipele idagba ninu emi
3. Ako tabi abo
4. Ireti ijo tabi afojusun ijo fun awon
akoko kan.
5. Irufe awon asese gbagbo ati oju
tuntun ninu ijo (ti o ba se ijo ajere okan)
IDURO
OLUKO NI YARA IKEKO

Eko, ayika tabi ibi ikeko, ipele idagbasoke ti oluko ati awon
akeko ati ipele oore ofe tabi ifororoyan ori oluko naa ni yio so bi yio ti duro.
Awon igba kan wa ti Jesu:
A.
Dide
duro. Lk. 4:17-19, Neh. 8:1-6
B.
Joko.
Lk. 5:1-3, Matt. 13:1-3
Sugbon oluko ni a ko reti ki o:
a. Beere mole
b. Ko joko dara sile
c. Lati fi ara ti opo
d. Duro laini ifojusun
e. Tabi ma rin kakiri
Ara iduro re ni imura re. O nilati
je:
a. Lati mo tonitoni
b. Ni iwonba tabi wa leto
c. Ki o fani mora
d. Ko gbodo si ara sile
e. Ki o woso bi Kristieni
f. Ko gbodo pariwo

AWON
OGBON IKONI
Awon ogbon ikoni nise pelu awon ilana ati ogbon ti a lo. Awon
eyi ti ama nlo ju ni eyi.
a.
Akeko
gbodo ko ipa ninu eko naa.
b.
Sise
apaare tabi bi fifi si ise
c.
Kika
jade-tabi siso tele oluko
d.
Akosori
Lk.24:25-27.
e.
Ilana
ibeere. Matt.16:13-19.
Kikoni. Lk
No comments:
Post a Comment