Wednesday, July 31, 2013

PRACTICAL ONE



GROUND OF TRUTH BIBLE INSTITUTE
No1, Aboderin Street Agbaje Orita Challenge Ibadan
EKO IFISISE (APA KINNI)

            
                 IWA L’ETO AWON EMI AIMO


Satani maa nfi ara re han bi eni ti o wa ni ibi gbogbo nigba kanna, ti o tumo sip e, o dabii pe o wa ni ibi gbogbo ni akoko kanna, sugbo otito ibe nip e o ni odiwon, ipa re ko si ju wiwa nibi kan soso ni akoko kan na lo.

Sugbon ohun ti esu maa nse nip e, o maa nso emi re di pupo ti yoo si to won leseese ni ona ti o je wipe enikeni ti ko ba mo ogbon ewe re yoo gbagbo wipe o (esu) wa ni ibi gbogbo ni. Ninu iwe Ifihan 2:13, Bibeli wipe ite satani wa ni Pagamu, sugbon bi igba ti o ti gbee kuro nibe ni lopo igba, lati igba na titi di oni yi ni a ti le ri ni ibi gbogbo sugbon kii se ni akoko kanna.

Satani nsise pelu opolopo awon emi aimo ti o to lona ti o dara. Ifihan 12:2,7 lara awon angeli ti o subu ni a pamo ninu ewon l’okunkun biribiri Juda 6.
      BI AWON EMI AIMO SE NTO
ARA WON NINU ENIYAN


Bi o ti nse ise iranse itusile, emi aimo akoko ti iwo yoo koko dojuko, paapaa ti iru ago bee ba nsa ipa pelu re ni; “Asiwaju / Abayagbangba” tabi “Igbakeji  emi aimo oloye” o maa nwa niwaju ni gbgogbo igba lati dojuko ohunkohun ti o ba fe ba ijoba won je, o maa nsaaba ba eniyan jiyan, ti iwo ko ba moo; nihin ni opo awon iranse itusile ti maa nni ijakule.

Ekeji ni emi aimo “Ojewewe”, awon wonyi je opo yanturu won si rogba yi oloye won ka, iru awon emi Aimo wonyi kii saba soro, ti won ba si fi’ya je won lasiko itusile, lesekese ni won yoo tu jade.

Ipa keta ni emi aimo “Oloye” tabi awon alase tabi adari gbogbo won, oun maa nduro leyin. Oun ni iwo yoo dojuko kehin, sugbon opolopo awon iranse  itusile ni won kii de odo awon wonyi ki o to su won, tabi ki won padanu ifamiororoyan won.



             AWON AMIN ENITI O WA LABE IDE EMI AIMO

Nipase kika Bibeli ati nipa iriri ori papa, ona meji  ni o ti di mimo, eyi ni ona ti o tayo afojuri ati ona afojuri.
Ona ti o tayo afojuri ni eyi ti Bibeli pe ni ebun imo emi yato ninu iwe I Korinti 12:10.

             APEERE NI WONYI:

1.        Peteru ati Jesu Oluwa.  Matt. 16:21 – 23.
2.        Ananaya pelu Safira ati Peteru. Ise Awon Aposteli 5:1 – 12
3.        Odomobinrin ti o tele Poolu ati awon iko re. Ise Awon Aposteli 16:16-18.
Ona ti a le gba f’ojuri, lati da eni ti o wa labe ide emi aimo mo ni yiye ise tabi ihuwasi re wo. Fun apere:


1.        Ti eniyan ba sun asunwora sugbon ti ko pa oju re de, ti dudu eyin’ju si ti ko wo’nu tan ti o si je wipe funfun oju re nikan ni a nri nita.
2.        Gegebi okunrin ara Gadara ti o ni emi aimo (Maku 5:3-4) paapa iyawo ile ti o tiju ti o si dabi eni ti ko le se jamba fun ni le pada je alagbara bi esin, ki o si je onipanle eniyan.
3.        Awon miran maa nni idaloro ninu eya ara ibalopo won, paapa julo isale ikun won tabi ki won ma le se deede ninu eya ibalopo won.
4.        Emi aimo ninu eniyan le gbe iru eni bee subu, ki o si se bii pe onitoun ti ku labe ise iranse itusile.
5.        Nigba ti omode ba nsoro loju o’run ti oro re si ni itumo koja sise iranran lo.
6.        Ti omode ba feran lati maa dawa ni oun nikan, ti o si nda soro laisi eniyan nibe.
7.        Eniyan ti o di eru iwa kan, eyi nipe ki iwa kan maa dari re; paapa lodi si ife inu re, fun apeere: ki oti mimu ti di baraku fun eniyan, siga, oogun oloro, tabi ibalopo ati bee bee lo. Mo fura gidigidi si emi aimo.
                     KIYESI AWON AMIN WONYI PELU

1.        Ti aisan ba ko lati kuro ninu aye eniyan, ti a ko si mo idi ti aisan naa fi nse e leyin ojo pupo, tabi leyin ti o ti lo si oniruuru ile iwosan kan si ekeji.
2.        Gbigbo ohun lati inu aye emi
3.        Ti awon ohun ti ko ye ba nrin ninu ago eniyan.
4.        Ni opo igba ni oorun sulfuru tabi oorun ti a ko le fi enu so yoo ma jeyo lara awon eni ti o ba wa labe ide emi aimo.
                         BI A SE LE DA EMI AIMO MO NIBIKAN

1.        Awon oorun ti ko ye lati gbo ni’bikan.
2.        Ayika ti o s’ajoji.
3.        Ifarahan awon  eda alaaye kan nibiti ko ye:
            i.          Okete ni osan gangan.
            ii.         Ki owiwi maa fo losan gangan.
            iii.        Ifarahan ejo ninu yara.
4.        Ki aja maa gbo lona ti o lodi.
5.        Ifarahan oyin t info ninu ile.
6.        Ifarahan oku ni‘bikan ati bee bee lo.
         BI A SE LE DA EMI AIMO MO NINU ENIYAN

1.        Ainaani igbe aye kristieni tabi ki ina Emi maa jo ajorehin.
2.        Iyemeji tabi aigba oro Olorun gbo, fun apere:
            a.         Aile fi igbagbo si ise.
            b.        Aini igbekele ninu Olorun ati ileri Re. Abbl.
3.        Asise ise isin. Eyi nipe sise ise isin ni ona ti ko to.
4.        Titako erongba awon elomiran patapata.
5.        Aile gba ibaptisi ti Emi Mimo.
6.        Aile gbagbo ninu Jesu tabi jewo Re ni Oluwa eni.
7.        Ki eniyan ma le ka Bibeli tabi aifokan si adura.
8.        Sise ohun ti o yato si ti awon eniyan ninu isin tabi opade.
9.        Sisoro lodi si Olorun tabi ise owo Olorun.
10.      Ero iku, fun apeere ki eniyan maa ronu lati pokunso.

 IFARAHAN EMI AIMO ATI IJADE
RE LAKOKO  ITUSILE

           Lati enu         

1.        Sisokun                                 2.    Bibu ramuramu                      3.    Igbe nla            
4.        Hihan gooro                                    5.    Yiyan lati bi                               6.    Eebi                   
7.        Iko wiwu                              8.    Gbigbiyanju                             9.    Didato lenu     
10.      Tituto                                     11.  Mimikanle                               12.  Gigunfe
13.      Kikerora                                14.  Yiyo ifoofo lenu                      15.  Pipohunrere
16.      Fifun ni orun                        17.  Didasoro                                   18.  Rirerin

        Lati imu        

1.        Mimikanle to lagbara                   
2.        Sisin               
3.        Dida ikun nimu
             Lati oju           

1.        Omije            
2.        Siseju pako-pako

      Awon Ona Miran


1.        Oogun kikan                       
2.        Iso siso                      
3.        Igbe yiya
4.        Oorun buburu                   
5.        Tito sara
               
   OJUSE IRANSE NINU ISE IRANSE ITUSILE

1.        Mase gba ese laaye ninu aye re. Jewo gbogbo ese ki o si ko won sile patapata ki o to bere ise iranse itusile. (Owe 28:13; Ps. 32:3,5; Matt. 5:48; 1 John 1:9)
2.        Mase fi okan so ohunkohun, ki o le se si olukuluku ni otito ati mimo gegebi o ti mo pe ise. Iranse Itusile nigbamiran ma nilo ati fi owo kan eni ti a nse sii.
3.        Mase ni ikunsinu, inu buburu tabi ikoro si enikeni. Dariji gbogbo eniyan, eyi wa fun rere ara re.
4.        Maa hu iwa kristieni ti o gbogbon bi kika bibeli deede, sisasaro, gbigbadura ati jijumose pelu awon onigbagbo yoku.
5.        Mase ko aawe sile.  Gba aawe nigbagbogbo, gba adura ki o si maa ka oro Olorun. (Matt. 17:21) So wipe ki a ma gbadura pelu aawe.
6.        Ti o ba mo pe o nilo itusile ni abala kan ni aye re, tara sasa ki o nii, re ara re sile niwaju Olorun ki o si beere fun itusile. Jeki awon omo Olorun ki o ran o lowo. Ninu ise itusile, okan ni wa, iwo na lee se fun elomiran.
7.        Mase jeki agara da o lati se ise iranse itusile fun elomiran bi o tile je wipe iwo naa si ni awon emi aimo kan ninu re, o nilo lati koko de won tabi ki o tete lo fun itusile tire na.
8.        Maa bere fun EJE JESU KRISTI nigba ti o ban se ise iranse itusile ki o to bere, laarin ati opin ise Iranse. Eleyi se Pataki fun idaabobo ara eni ati ijagun emi.
9.        O gbodo ni ife ati ikaanu fun eni ti o ni emi aimo ki o ba le ran lowo daradara.
10.      Gbe igbe aye to koja egan ati itiju, o gbodo je oniwa rere. O ko gbodo mu egan ba oruko Kristi tabi ise re laye.
11.      O nilo suuru ninu ise iranse. Mase kanju, ki o ri daju pe ati tu eni ti a nse ise iranse fun sile.
12.      Maa ko akosile ohun gbogbo ti o ri ni papa itusile. Kowe lori ise iranse kookan, mase gbagbe lati Ko ibi, ojo, Iranse Olorun ijo naa, akori eko, oro iyanju ati ohun ti Olorun se nipase re nitori Olorun nko wa ni ojoojumo.
13.      Mase so asiri aye eniyan si ita, eyi ti a so fun o ninu ise iranse  itusile  tabi igbanimoran. Ti o ba s’eleyi, Olorun yio fiya je o, Satani  paapaa yio fiya je o.
14.      Mase fi dandan gbon pari ise iranse nigbati o mo wipe o si nilo awon asiri kan nipa eni ti a nse ise iranse itusile fun tabi nigbati ijiya lowo awon emi aimo ti o njade lara re ba poju. Fi gbogbo emi aimo ti o seku sabe ide di ojo miran.
15.      Bi a ba nse iranse pelu awon osise itusile miran, enikan yo saaju bi emi mimo ba se dari. Mase je ki so owo tabi ese po tabi se amin.
16.      Nigbati a ban se ise iranse itusile ni awujo ti emi aimo ba si farahan lara enikan ninu awon osise itusile, o le se awon ohun wonyi: 1. Tete mu lo si apa kan.             2. Tete de emi aimo ti o wa lara re ki iye re sibo sipo.   3.  Je ki o lo joko si ibomiran ti ifamiororo yan ko le de, titi ara re yio fi wale
17.      Mase se itusile fun eniti ko iti ni ipinnu ati fi aye re fun Jesu ati lati rin ni ominira titi ojo aye re. (2 Kronika 12:14) Nitori emi aimo na ki yio jade, bi o ba si jade, yio pada laipe pelu emi aimo meje miran pelu re ti o buru ju lo.
          AWON OJUSE ENI TI O NILO ITUSILE

1.        Jewo Jesu ni omo Olorun, Olorun awon Olorun, Oluwa ati Olugbala, kuro ninu ese, Eyi ni ilepa ti o se Pataki julo fun aiye onigbagbo oun si ni kokoro lati pari ise iranse itusile lowo ota.
2.        Jewo gbogbo ese ikoko, koo sile ki o si toro idariji lowo Olorun.
3.        Jawo ninu gbogbo egbe okunkun fun apeere aje, ise satani.
4.        Kede idariji si gbogbo eni ti o se ibi si o ati awon ti o ni sinu, korira tabi lodi si. Bakanna ki a dariji  awon asiwaju ti o ti ko wa wo inu ide loni. Eyi lagbara ti won ba le so oro ibukun sinu aye awon ti won se won ni ibi. Luku. 12:4.
5.        O gbodo ko ni gbangba emi ti o ba gbagbo pe o wa ninu oun.  Ki o so gbogbo oro asiri ara re ni akoko igbaniyanju lati le daabobo  asise itoju ti ao fun un.
Leyin gbogbo iwonyi, ti emi aimo ko ba jade ni idahun si ase wa, o san ki a yera fun ise iranse gigun, ki a ma tun maa se awon ohun ti a ti se tele. Dipo bee, wo awon nkan wonyi siwaju sii.

1.        Ise okunkun ti a ko jewo, ko sile, ki a si dojuko.
2.        Ese ti a ko jewo re tabi ti a ko ronupiwada re, nitoripe ko le si ijewo laisi ironupiwada
3.        Aisi ife inu lati di ominira
4.        Aisi igbagbo pe Kristi ti mu ojulowo ominira wa
5.        Ese irandiran; sise agbeyewo itan idile le je iranlowo.
                IWAASU NINU ISE IRANSE ITUSILE
 

                                                






Iwaasu ninu ise iranse itusile ko dabi awon eto miran yoku nitori awon nkan wonyi:
1.        Akori ti a o yan gbodo wa ni ibamu pelu ise iranse itusile
2.        Iwaasu na gbodo le fun awon olugbo ni eko nipa ohun ti itusile da le lori, “eyi nipe ounje omo ni”
3.        Awon asiri emi aimo miran di titu jade.
4.        A gbodo waasu ihinrere Jesu Oluwa wa ki a si gbaaye fun awon elese lati ronupiwada.
5.        Bi won yoo se wa ni ominira leyin itusile, eyi nip e ki won yago fun ese gbodo je ohun ti a o tenu mo.

GROUND OF TRUTH BIBLE INSTITUTE
No1, Aboderin Street Agbaje Orita Challenge Ibadan
PRACTICAL ONE
               THE ORGANISATION OF DEMONS
           
Satan presented as if he is omnipresent, that is he seems to be present everywhere at the same time, but the facts is that he is limited to one geographical location at a time.

            But what the devil does is that he re-produce his spirit, and he organized them in such  a way that those who did not know his tactise will believe that he (satan) is ominipresent, In Rev 2:13 Bible said satan’s seat was at pergamos, but he has likely moved it several times since then and today he can be find at any where.

            Satan operates a well organized multitude of demons: Rev 12:4,7 some of the fallen angels are even now reserved in chains under darkness Jude 6.
                         ORGANISATION IN A PERSON
           
As you are ministering deliverance, the first demon to face, especially if the victim get violent with you is: “Frontier or Deputy chief demon” he always stay in the front to attack anything that want to tamper with their kingdom, he always ague with you, so if you don’t know him it is at that point that many deliverance minister get discouraged.

            Second one is the lesser demon, these set of demons are always numerous and they surround their chief, these set of demons don’t usually talk and when tormented during deliverance ministration they take their leaves and go out.

            Third set is the chief demon or the leader or commander of all, he stay at the back, so you will face him last, but many deliverance minister will not even get to this one before getting discourage or lose their anointing.
                    SYMPTOMS OF PEOPLE UNDER DEMONIC BONDAGE

            From the reading of the scriptures and from field experience, there are two methods that have been discovered are Supernatural and Natural.
The supernatural way of determining the presence of demons in you or in someone else is by what the Bible calls discernment of spirits in 1 Cor 12:10.


            EXAMPLES ARE:

1.        Peter and the Lord Jesus. Matt. 16:21-23
2.        Ananias and Sapphira versus Peter. Acts of Apostle 5:1-12
3.        Young girl who followed Paul and his team.  Acts 16:16-12
The natural way of identifying people under demonic bondage is by examining their actions and reactions. e. g.
1.        Sometimes people fall into a trance. Their eyes are closed and when you open their eyelids their eye balls roll back and the white parts show.
2.        As with the demon possessed man of the Gerasenes of Mark 5:3-4 even the most timid and harmless house wife can become as strong as an ox and violently.
3.        Some people suffer from organic disturbances, especially in the stomach region.
4.        The evil spirit in the person may cause him to fall down and act as if he is     dead under deliverance ministration.
5.          When children always talking in the dream some reasonable sentences.
6.        If a little children love to isolate himself to a secret place and always talking   alone.
7.        A man who is a slave to any habit, that is, when a habit is controlling you,
             even against your will or desires, e.g. addition to alcohol, cigarettes,              
             drugs,  sex. e.t.c. I strongly suspect demons.
        WATCH OUT FOR THE FOLLOWING SIGNS ALSO

1.        When the sickness has not been cured nor has it been identified nor has its cause been known after a long time or after having been to one or many hospital seeing doctors.
2.        Hearing of voices from the spirit world.
3.        Unnatural feeling of movements in various parts of body.
4.        At times a smell like sulphur or other noxious aromas will come from the person who is under demonic bondage.
       HOW TO RECOGNISE DEMON IN A PLACE

1.        Unnecessary odour in a place
2.        Strange atmosphere
3.        Unusual manifestation of certain creatures. e.g.
              i.        Big rat in the day light.
             ii.        Owls flying about in the day light.
            iii.        Appearance of snake in the bedroom.
4.        Unusual barking of a dog.
5.        Manifestation of the bees in the house.
6.        Manifestation of ghost in a place, e. t. c.

             RECOGNISING DEMON IN A PERSON   

1.        Useless of Christianity in a life of person or spiritual deterioration
2.        Doubt and unbelief concerning the scripture, e.g.
            (a)  Inability to exercise faith
            (b)  Distrusting God and His promises e.t.c.
3.        Religious’ error, that is, committing error always on spiritual assignments.
4.        Extreme antagonism that is not submitting to other people’s opinion.
5.        Inability to receive the Baptism of Holy Spirit.
6.        Inability to believe Jesus or to confess Him.
7.        Inability to read bible or concentrate in prayer
8.        Irrelevant action in the time of service or any meeting.
9.        Blaspheme to God or his work, or Opposition to God.
10.      Thought of death e.g. thoughts of suicide.
DEMON MANIFESTATION AND MOVING OUT
DURING DELIVERANCE MINISTATIONS

   Through the mouth         

1.        Crying                                        2.  Roaring                             3.  Loud shout
4.        Shrieking                      5.  Yawing                             6.  Vomiting 
7.        Coughing                      8.  Retching                           9.  Drooling
10.      Spitting                        11.  Sighing                                       12. Belching
13.      Groaning                    14.  Frothing                          15. Moaning
16.      Choking                       17.  Soliloquizing                 18.  Laughing

              Through the Nose              

1.        Deep Noisy Breath – Exhalation
2.        Sneezing
3.        Spontaneous Oozing of phlegm from the nose.
                             Through the Eye                            

1.        T ears                   
2.        Blinking

           
        Other ways

1.        Sweat in profusion
2.        Gas-Effluvium
3.        Excrete
4.        Terrible Odour
5.        Urination (and contours)
 THE RESPONSIBILITIES OF A DELIVERANCE MINISTER

1.        Do not tolerate any known sin in your life. Confess all sins and forsake them even before you step in to deliverance ministration proverb 28:13; Ps. 32:3,5; Matt 5:48; 1 John 1:9.
2.        Keep your mind on a NEUTRAL gear emotionally to be able to deal with everybody in righteousness and holiness, as you know that deliverance ministration at times may require that you touch the victim.
3.        Never cherish resentment, ill-feelings or bitterness against anybody. Forgive them all, this is four your own good.
4.        Cultivate strong Christian habits like regular Bible reading, meditation and prayer and fellowshipping with other believers.
5.        Do not neglect fasting. Fast regularly and pray and read the word Matt. 17:21  means that prayer should go along with fasting.
6.        If you know you need deliverance in any area of your life, hurry up and  get it; Humble yourself before God ask for deliverance, and let the children of God help you. In deliverance world, all of us are one, you too can do it to another person, so NO SUPER STAR.
7.        Do not be discourage from ministering deliverance to other, even though you still have some demon in your body, but you need to first bind them or you quickly find how you will be delivered.
8.        Do plead the BLOOD OF JESUS CHRIST always when ministering deliverance, Before, During and After. This is very important for your defence and for attack.
9.        You must have love and compassion for the demonized in other to be able to help them effectively.
10.      Live above reproach and public blame. Be a man or women of good character and report, thou shall not bring reproach upon the name of Christ or upon His work on the earth.
11.      You need patience during ministration, don’t be in hurry so to move sure the victim is been delivered.
12.      Keep records of your findings in the deliverance field. Write notes almost each ministration, don’t  forget to state clear the place, date, minister in charge, topic, the message and what happen even through you that day for God teaching us day by day.
13.      NEVER, NEVER tell the secrets of people’s life, which they told in confidence during deliverance or counselling session. If you do, you will be punished by God – even by Satan also.
14.      Do not insist on finishing the deliverance at all costs, even when you know that you still need some information about the victim, also when you know that the victim has taken a lot of punishment from the fleeing demons and then you need to call deliverance off by boxing the reaming demons.
15.      When ministering with other, deliverance workers, one of you should lead as the Holy Ghost directs, and do not allow joining of hands or legs together nor saying. Amen
16.      When ministering deliverance in concert and one of those ministering the deliverance begins to manifest demons, you can apply these:  1. Take the person aside.   2.   Quickly bind all the demons on him/her.   3.   Take him or her to a place that is far from the anointing for rest
17.      Do not go ahead to minister deliverance to anyone who is not yet ready to walk in freedom all the days of his or her life 2Chronicles 12:14. Because the demon will not go, and if he goes at all, it will come back sooner or later, even with another seven demon that are wicked than him.
RESPONSIBILITIES OF A PERSON
WHO NEED DELIVERANCE

1.        Confess Jesus Christ as the son of God; the Lord of all and their personal Lord and Saviour from sin. This is the all important goal for every believer’s life and the key to complete deliverance from the enemy’s hold.
2.        Confess all known personal sin ask for God’s forgiveness.
3.        Renounce all occult involvement e.g. witchcraft, Satanism  and freemasonry by themselves or their ancestors.
4.        Speak out forgiveness to all who have caused hurt and against whom they have harboured bitterness, resentment or hatred. Also forgiveness should be spoken to their forbearers for actions which have caused spiritual bondage that affect them today. It is powerful if they will speak words of blessing to these who did them wrong. Luke 12:2
5.        Renounce any spirit to be present in them. Tell the correct story of yourself during the counselling hour to prevent wrong prescription.
Having done all these and the demon did not leave in response to our commands, it is better to avoid prolonging the ministration, repeating what you have already done. Instead look further at:
1.        Occult practices not confessed, renounced and dealt with.
2.        Sin unconfessed or not truly repented of because there can be confession without repentance
3.        Lack of real will to be set free.
4.        Lack of faith that Christ has brought about complete freedom.
5.        Sin by ancestors; “Tracing the family back-ground may be of help”

PREACHING IN DELIVERANCE
MINISTRATION
 







Preaching in deliverance ministration or service is not like other programme because of the following:
1.        The choose topic must relevant to the deliverance ministration
2.        The message must educate the listener about what deliverance is that is “food of children”
3.        Some of the secret of demons must be reviled
4.        Gospel of our Lord Jesus must be preached, and allow the sinners to repent.
5.        How to stay free after the deliverance that is to abstain from sin must be emphasized.

No comments: