MOBILE 08056008526.
HANDOUT
IJERE OKAN NI RIRE
ASA KOJA
THE BIBLE
CULTURE
THE MISSIONARY CULTURE THE RESPONDENT CULTURE
ADVANCED CHRISTIAN LEADERSHIP (100 LEVEL)
IJERE OKAN NI RIRE
ASA KOJA
Ijere
okan ni ona rire asa koja tumosi, sisalaye Kristi ni ona rire asa koja. O
tumosi wiwasu ati kikoni ni eko ihinrere ti Jesu Kristi ni rere asa koja.
Matt.28:199-20, Mk.16:15-16, Rom.1:16
ASA
·
Asa ni a le sapejuwe re gigibi,
akojopo orisirisi awon ohun ti a gbagbo, lori ihunwasi, ati irufe ona ti a gba
huwa, imolara ati ifesi.
·
Asa tumosi akojopa orisirisi igba
nipas Olorun, tabk otito, tabiotito, tabi itumo ti o ba mu.
·
Asa tumosi akojopo awon ohun ti o
niye lori nipa ohun ti o je otito, ti o dara, ti o lewa, ati ti o siri bi o ti
ye ki o ri.
·
Asa tumosi akojopo awon ihunwasi
baaku, bi a t le se si elomiran, isoro, adura, iwoso, ise, Ere idaraya, Okowo,
Ise agbe ati bi a ti n nje.
ELEGBEJEGBE AWON ENIYAN
A pin awon eniyna si isori isori ti a fi le sawon
mo gege bi won ti ni olajusi, ti won si sakiyesi ara won pea won ni iseda Ede
ti o jora, Nitori ede kanna ti won nji nso, esin kanna, ijogba ilu kanna, jije
iru onje kanna, ati didojuko iru isele kanna tabi apapo gbogbo nkan wonyi.
BI ASA SE JINA NINU ISE IJERE
OKAN LATI E0-E3
KAA: ACTS
1:8
Lati kede ijere okan
fun omo ijo ti o ti wa, tabi
onigbagbo afenuje
EDE KAN NA
ASA
KAN NA
IGBAGBO
KAN NA JERUSALEM
SUGBON KO DI ATUNBI
E1- IJERE OKAN
Lati kede ijere okan fun
fun awon eniyan ti igbagbo won
yato, sugbon ti won
ni asa
ati ede kanna
EDE
KAN NA
ASA
KAN NA
SUGBON
IGBAGBO OTOTO
JUDEA
KO
SI DI ATUNBI
Akiyesi: E0-
AMAA NSE ISOJI NINU IJO ATI IMUDAGBA KRISTENI
E1- A NSE ISE IJERE OKAN TI ALASA KAN
TABI TI ALADUGBO
E2- IJERE OKAN
E2-
IJERE OKAN
Lati kede ijere okan fun
fun awon eniyan ti igbagbo won
yato, ti won si nso ede
kanna
EDE KAN NA
ASA
OTOTO
IGBAGBO
OTOTO SAMARIA APEERE ACTS 6: 1-7
SUGBON
TI KO SI DI ATUNBI Awon opo Heleni ati awon
opo Heberu Acts 8: 5-40
E3- IJERE OKAN
Lati kede ijere okan fun
fun awon eniyan ti igbagbo won
yato, ti ede ati asa
won yato
APEERE Acts 14: 1-28
EDE
OTOTO
ASA
OTOTO
IGBAGBO
OTOTO TITI DE OPIN AYE
SUGBON TI
KO SI DI ATUNBI
NINI OYE ASA
Ajinhinrere ati ojise Oluwa ni ojuse lati kede eko
igbala ti jesu Kristi,ti o ba bibeli mu ni ona ti o re koja Ogiri Asa.
Lati se eyi, won gbodo ko bi a tin so oro Kristi
fun awon olugbo ni ona ti o gba b aero okan won, isowo lo ede, isesi won si
awon ikede, ogbon sise ipinu, ise ati ifesi pelu iwoye aye.
Ojuse Ajinhinrere ati ojise Oluwa naa ni lati fi
otito to bori asa, ti bibeli fun eniyan ti o nbe ninu ide asa.
AWON ASA TI OTITO BIBELI GBA KOJA
OTITO TI O ASA ASA
ASA AWON ASA ASA
BORI ASA HEBERU GRIKI OYINBO AYE
OIWASU ASE ENI TI
ODE ONI
ANBA SORO
1.
Ihinrere naa kun fun otito ti o
bori Asa.
2.
A mu to eniyan wa ni asa Heberu
ati Giriki.
3.
Ti a tumo fun wa ni Asa awon
Oyinbo.
4.
Ti a si gba lati inu asa tiwa.
5.
Ase naa ni yio se asa eni ti a
nba soro.
DID TI A FI NKO ASE NINU ASA
Ki o to le wasu ihinrere ni ona ti o mu ina
doko fun awon eniyan asa miran ki o sit un duro gege bi otito ti o bori asa, o
gbodo koja laarin ase ti o se, ki o ma ba seese fun awon asa t o gba inu won
koja lati sodi adalu (Porukumusu).
OLORUN
PETERU KONILIU
ASA HEBERU ASA
ROMU
AKIYESI
1.
Ibasepo ti o kuna wa larin Peteru
ati Olorun.
2.
Peteru ni a ran lati wasu fun
koniliu.
3.
Koniliu da Olorun lohun.
4.
Peteru ni idaniloju pe Koniliu ti
yipada si Olorun.
·
ELEYI NI A NPE NI IJERE OKAN ATI
IBANI SORO NI ONA RIRE ASA KOJA
·
OTITO
NAA TI O BORI ASA NI AKO GBODO KUN LODA.
ASA BIBELI
AKIYESI:
Gege bi
Olubanisoro Onawasu duro ni agbedemeji o si now ona mejeji.
A1.
O koko wo Iwe Mimo.
2.
Oro naa ki ise ti ara re.
3
Ohun ko ni orison re.
4
Ko si nibe nigbati akoko fi fun
ni.
5
Oro ti ara re ko ni imisi gege bi oju iwoye
bibeli.
6
Ohun ko le so gege bi awon
Aposteli Rev.22:18-19, 1John.1:1-2.
7
Ojuse re akoko ni ki o ka Bibeli,
O darajulo ki o ka ni ede ojulowo sugbon o gbodo fi gbogbo igba fi ola fun asa
Bibeli.
8
O gbodo se agbekele iwasu re fun
eniti o nbe soro nipa igbagbo.
B1 Nigbati oniwasu
bag be oju re soke ti o si wo papa o nri awon ogoro ero ti won nilo ihinrere.
2
Eyi ni Jesu ri ninu
Matt.28:18-20.
3
Sugbon oniwasu now asa eniti o
nba soro.
4
Oniwasu gbodo mo pe oun ki se
orison tiwatiwa,
5
Isoro eniti a nba soro lati inu
asa re yio ma fu gbogbo igba sajoji si tiwa.
6
Asa eni naa t a nba soro, yio je
asa ti oniwasu tewogba funrare.
AKIYESI:
1.
Oro oniwasu gbodo je lati inu
bibeli.
2.
Olorun lo fi fun nipase Aposteli
ati awon woli ni eda ati asa bibeli.
3.
Asa bibeli ni o ni itoka si
gbogbo asa t o ku ninu, nibi ti a ti mu ojulowo iwasu bibeli jade.
4.
Oniwasu naa je eniti asa tira ko
fara han bi o ti le ni asa ti o yato si ti bibeli.
AWON APERE IYATO TI O WA LARIN ASA
1.
Locust: Ounje Johanu.
Locust: Igi kan ti o ni eso.
Losust: Ni ile Yoruba o je kokoro kan ti o ma
nba irugbin je (tata bakanna ni no tun tumosi IRU ti a nfi si obe (wo Matt.3:4;
Lev.11:2).
2.
Hand: Ni ile Yoruba of tumosi
Owo.
Owo: Ni ile Ghana o tunmosi Ejo.
Amu: (Ikoko omi) ni ile Yoruba, ni Ebira o
tumosi Fila.
IBANISORO TI ASA
Ibanisoro ni ona ti o re asa koja, ni ona ibaniso
awon otito, awon idajo, awon ero tabi otito inu okan eniyan kan tabi awon
eniyan ti won ni asa kanna de odo eniyan kan
tabi awon eniyan ti o ni oniruru asa.
IBANISORO
Ibanisoro je ona fifi ifitonileti ranse si awon egbe
miran.
Gege bi Aristotole, okan lara awon onimo ijinle ti
so, o tumo ibanisoro gege bi ona kan ti a le gba salaye ero okan eni jade.
Ibanisoro je ona fifi oro, ifitonileti, ero tabi
imolara ranse si elomiran ni ona ti oye kikun ati pipe yio fi wa ninu okan eni
ti a nba soro, ibanisoro ko ti waye.
Ibanisoro pin si ona meji, ibanisoro ti oro tabi
ti alapejuwe.
OLUBANISORO
NAA:
Olubanisoro je a ba ni soro ti o ni ero, ife inu, imolara, ati ifoju
woye ti o fe fi ranse si elomiran.
Isoro ti oluanisoro n dojuko ni ati mo Ede ti
eniti a naba soro loye re, Ede je ona kan soso lati banisoro. Nitori idi eyi, o
je ojuse olubanisoro lati mo awon ti o fe ba soro, ki o to bere igbese
ibanisoro re.
OLUGBO
ORO NAA: Olugbo ni eni naa ti o gbo oro lati enu oluso.
Olugbo oro naa ti gba oro naa nigbati o ni oye ohun ti oro naa tabi ifitoni
lati naa nso.
O je ohun ati o dara lati mope ibanisoro nlo ni
gbogbo wakati merilelogun ti o nbe ninu ojo. Otito ti o daju nip e aye gan duro
lori ibanisoro, oku nikansoso ni kole banisoro. Ibanisoro nlo nibi gbogbo.
IBANISORO TI OLORO ENU
Ibanisoro ti oloro enu ni lilo oro lati fi ifitoni
leti ranse. Iru awon wonyi ni a le ko sinu iwe nigba miran. Oluso oro ma n nlo
ede ti olugbo looye lati fi soro re.
IBANISORO TI ALAPEJUWE
Eyi ni fifi oro tabi ifitonileti ransenipe apere
tabi ami e.g. nigbati oko ban tan ina sejuseju tabi nigbatyi okunrin kan nba
nsun labe iwasu oun ti o nso nipe oniwasu na ko so asoy e oro. Yiya ofa si ara
patako, aso apajuwe ati ise alemo ogiri etc.
ARIWO
NINU IBANISORO
Ariwo ni ohunkokun ti o ba di idanisoro ati iloye
oro lowo. Osiri asiwo meji lowa: eyiti ro (Elero/Mechanical) abi ti asilo oro
(semantic).
ARIWO
ELERO: Ariwo ti elero ni idiwo ti o ma nti ipase awon
ohun ti o nrin wa, boya ero ti o sise tabi lati odo awon ti o nsoro ni tosi odo
wa, o le je ekun lati odo omo kekre, erokero ninu okan, ariwo pipa ninu
ibanisoro eyi ti ko wulo ati beebe lo.
ARIWO TI
ASILO ORO: Ariwo-asilo oro je eyi ti o ma nwa latari ailoye
nipa lilo awon oro ti ko ba ogbon mu
tabi lilo awon oro ti itumo re kii tete yeni. Awon elomiran ma nlo awon oro ti
itumo re kii tete yeni lati fi gbayi loju awon olugb, ti o si je pe abajade re
je iporuru okan fun awon olugbo.
AWON OHUN TI A NI LATI YAGO FUN
NINU IBANISORO
1.
IRIWO
TI KONI ITUMO: Opo oluso tabi oniwasu lode oni ni won rope
agbara oro siso wa ninu ki a ma pariwo sa. Ariwo ko ni ohunkohun pelu ifororo
yan.
2.
IRIKERINDO
TI KO BA OGBON MU: Akole sa fun irin sotun tabi
sori ninu ibanisoro patapata, subgon ti o ba poju yio tumosi ariwo.
3.
ATUN
WI AWON ORO: Awon oro bi ke “Haleluyah”, “Amin” ni a le
lo ni ona to ba ogbon mu won kise oro ti
a ma nlo nigbati a lo ba ri oro so mo.
4.
YIYA
KURO LOJU ONA TI KO BA OGBON MU: Nigba mira oluso a maya
kuro loju opo ti oun to bo ninu ibanisoro re. sugbon nigba miran yiya kuro loju
ona yii ma nfa idarudapo ninu ibanisoro. Eniti a ni ko soro laro omi sugbon
nitori o feran ina ju omi, o wa soro pupo lori ina ju omi lo; iru eni bee ki se
oluso ti o mu inadoko.
5.
FIFI
IMO TI KO TO HAN: A ti ri fun opo odun sehin pea
won eniyan feran lati ma nso nipa aseyori atijo, won o ma toka si iwasu won ti o koja ti won
wa nibi kan eyiti konise pelu iwasu ti lowolowo.
6.
IWA
IBAJE NIPA AKOKO LILO: Lilo akoko wa lara ibanisoro ri
daju pe oro re mo niwon, nitoripe kip e ti oro fi nsu awon eniyan.
7.
ISOPO
ARA ENI: Nigbati o nba soro papa ninu ijo, jowo year fun
isoro ara re tabi larin iwo ati enikan ninu oro re. Jowo sora nipa isoro awon
eniyan.
8.
PIPARI
IJA: Opo awon iranse Olorun ni won ti gori aga iwasu,
pelu iwasu akanse ati doju ija kan enikan ti o sewon ninu ijo. Eleyi ki ise
ibanisoro rara. Ti o ba ni wahala pelu enikan ninu ijo, ori iwasu ko ni a t
nyanju re. Jakobu.3:2-6.
ILEPA
OLUBANISORO (ROM.10:11-15)
1.
Lati ni aridaju liloye ihinrere.
2.
Lati ni aridaju liloye, a gbodo
ni oye bi awon eniyan ti ma n’ni oye.
3.
Olubanisoro gbodo pese ihinrere
gege bi ohun ti oye ki a mo ki a si tewogba.
4.
O gbodo wasu ihinrere ki awon
eniyan ba le ni oye ti o kun nipa oun ti ihinrere je.
SISO ASOYE ORO NINU ASA KAN
Eyi
tumosi jije ki oye oro ki o ye ni, ki o si ni itumo lati inu asa kan. Asa
Kankan ni o ni ero tire nipa awon ohun ti o je otito, bakanna ni o ni ona ihuwa
pelu itumo re.
Iwa
kanna le ni itumo kanna ninu asa ototo. Fun apere.
1.
Ero nipa idaniloju otito pe
orisirisi.
2.
Iwa orisirisi leni itumo kan
soso.
3.
Iwa kanna leni itumo orisirisi.
4.
Awon feran ohun ti o ba je tiwon.
Won ma feti si orin oro ati iseto eyi ti o debi iru eyi ti won tin se tele.
AWON IHUWASI ONA IBANISO ASOYE
LATI INU ASA
1.
O gbodo le so oro naa ni asoye
ati ni ekunrere.
2.
O gbodo mu idaniloju ati nini se
olugbo oro na lowo. Isoro ti won dojuko ni a gbodo yanju ati iru iyan ti won ma
nja ni a gbodo lo lati dawon lejo.
3.
O gbodo reti iyipada asa bi o ti
wun ki o kere to lati odo olugbo oro naa. (Act.13&17). A ko gbodo so pe ki
won yi asa won pada ni awon ona ti Bibeli kop on ni dandan fun won lati yi
pada.
AWON
IGBESE LATI DE ODO AWON ENIYAN TI A PATI
1.
SISE
AWARI: Igbsese akoko ni lati se awari ibi ti awon wniyan
ti a pati wa tabi ibi ti won ngbe. Eleyi ni awari awon iranse Olorun. O le losi
ijoba ibile ipinle tabi awon oba alaye (Oba tabi Baale) lati bere iru ede ati
asa won (Taraba ati Adamawa ni awon eya ogorun) bi o ko ba se iwadi o ko le mo
awon eniyan ti a pati. Ijoba ibile kan ni Ilorin nile ijosin merindinlogun pere
(16). Won se ikede eyi, isoji ni o si tele.
2.
JADE
TO WON LO: Lara isriranse nla ni lo- Nigbati a bi ti ri awon
ti a foju sun, igbese to kan ni lati lo gbe ni arin won. Eyi a ma mu iponju wa
ni igba miran.
3.
KIKO
NIPA IWOYE AYE WON: Niwon igba ti o wa larin won, wa
bere si ni ko nipa iwoye aye won. Kinni won rope o je ojulowo ati kini ero won
nipa esin? Kiko nipa ede won yio ran wa lowo lati ni oye won. Eleyi yio ran wa
lowo lati mase asise nigbati asiko bato lati gbe ihinrere kale.
4.
KIKO
NIPA AWON AINI WON: Bi Kirsti b aje idahun, kini
ibere? Bi awon eniyan ko b ani aini ohun ti Kristi fi fun won ko ni le je ohun
iyebiye siwon (e.g. won le ma beru aje ati emi buburu. Je ki won pe Jesu le ba
aini won pade.)
5.
AGBARA
ATI ADURA: Kosi eniyan ti o tobi ju igbe aye adura lo ni opo
igba, bi o ti le jepe a gbe iwasu ihinrere kale ni ona ti yio gba ye won, sibe
won ko tewogba { wo (2Kor.4:4) ki o si sakiyesi re si Matt. 13:19} abayori kan
soso ti o wa fun eyi ni adura. Ajinhinrere nilo igbe aye adura ti o duro sinsin
fun awon eniyan ki okan won le di ominira ki won ki o le ni oye ati ki won ki o
si tewogba ihinrere.
6.
MIMU
BIBELI TI WON NILO JADE: Bi elegbejegbe awon eniyan ti
bere sini dahun si ihinrere, ajinhinrere nilo lati sowon di omo eyin, sugbon
iru ohun elo wo ni yin lo? Nigba miran gege bi ajinhinrere o le ri awon ohun
elo ti a ti pese sile ti yio sise daradara ni aagbegbe re nigba miran o si le
nilo lati pese fun ara re.
7.
OMOLEYIN:
Asese gbagbo nilo ki a so di omo leyin, ki a si mu dagba di ijo ti o ni agbra
ti o le ma ran awon iranse jade. Ajinhinrere nilo lati kowon ki o si gbadura
fun awon asese gbagbo.
8.
IPO
IHINRERE NILE ADULAWO: Awon eniyan ti le ni ogorun mejo
million (800 million) ni o ngbe nile adulawo. Eleyi je idamewa ero ti o wa ni
gbogbo agaye, ile adulawo ni o si ni ero ti o po julo nile agbaye (won ma nle
idameta ni ododun). A pin ile adulawo si ede ona (1,730 languages) ti o je ida
kan ninu meta ede ti o wa ni gbogbo agbaye. Awon idaji ede wonyi ni won si nilo
ki a tuu bibeli se ede won.
ile adulawo ko ni awon ilu nlanla bi awon
ibomiran ni agbye. Awon ilu bi ogbon ti o ni ero ti o le ni million (over one
million), sugbon awon orilede miran
koni awon ilu nlanla bee. Ni akojopo
opolopo awon eniyan kakiri agbaye ni wo si ngbe ni igberiko.
Ti a bawo awon eniyan ti o ngbe ni arin odo
kakiri ile adulawo a o ri orilede merinleladota (54) nile adulawo. Sugbon awon
eniyan wonyi ko se pin dogba dogba larin. Idaji gbogbo ero ti o wa ni ile
adulawo ni o ngbe orile ede mefa pere awon orile ede bi (Nigeria, Egypt, Ethopia,
Zaire, South Africa ati Morocco)> gbogbo awon ti o ku ngbe ni awon orile ede
mejidinladota (48) ti o ku. Mejo ninu awon orile ede adulawo ti o ku ni won ni
eniyan ti ko to million kan (1 million). Bi o ti le je pe ile adulawo ni
orisirisi ede sugbon opo awon orile ede
adulawo ni won nlo ede Geesi gege bi ede orile ede won tabi ikan lara ede orile
ede won. Eleyi ran ibanisoro lowo papa julo ni awon orile ede ti o jepe won nlo
ede tiwatiwa. Ede Geesi ni won nlo ni orile ede metadinlogun (17) nigbati won
nlo Faranse ni awon orilede mejilelogun (22) won sin lo ede Potuga ni awon
orile ede marun (5). Awon orile ede Ethopia ati Eritrea ni won je orile ede ti
o nlo ede adulawo eleyi fi han wo bi o ti niran lati ba ni soro kikiri agbaye.
Ti a b nsoro nipa esin ni ile idulawo, idagba
soko nla loti ba esin omo lehin Kristi ninkan bi ogorun odun seyin (100yrs). Ni
odun 1900 awon omo lehin Kristi ti di million mejo Kakiri ile adulawo sugbon
loni won ti ju million 330 lo. Bakanna
ni awon musulum ti le ni odunrun million (300 million). Idaji awon wonyi ni won
wa ni Gusu asale sahara. Awon musulumi ni won po yaturu ni Comoros, Djibouti,
erptrea, Gambia, Guonea, mali, Niger, Sanegal ati Somalia bakanna ni wo tun wa
ni Mauritiania, Morocco, Tunisia, Algeria, Libya, Egypt ati Sudan. Awon eniyan
gusu ile adulawo sara ni won si sin awon esin wonyi, ti won je bi million
metadinlogorun eniyan (97 million people)
Awon elesin ibile wonyi ni ero ti o poju ni
awon orile ede bi Benin, Guinea- Bissau, Mozambique and Sierra Leone. Oke
aimoye elesin Kristi ati awon elesin munulumi ni won si ntele awon esin atijo
yi labenu.
Opolopo awon orileede ni idaji Gusu-agbaye ni
ogoro won je omo lehin Kristi. Idaji onigbagbo ajinrere ni o n gbe ni awon
orile ede meta bi Nigeria Kongo (Zaire) ati Kenya. Ida meta awon ajinrere ti o
ku ngbe ni South Africa, Uganda ati Ethopia.
O fe re to idaji awon Ajinhinrere ajoji ti wa
ni ile adulawo ti won si sise ni awon orile ede mefa, die ninu awon orile ede
won nibi ti awon ijo ti kere ni o je pe nitoripe awon ijob ti o koja lo ko
feran awon Ajihinrere wonyi, won ko si fi aye gba won.
Ni Nigeria opolopo awon eniyan ni won koni
fani ti o po si ihinrere. Bakanna ni awon opolopo eniyan wa ti o je pe die ninu
awon eya won ni won ni ile ijosin nigbati awon iyoku ko ti le ni. Awon eya kan
wa ti wo je onigbagbo sugbon die ninu won ni o ti yipada nipa Kristi. Awon ifitololeti
nipa awon eya ti o wa ni oke oya ni ni a ti gba ki a ba le mo ipo ti won wa
nipa tie mi. opolopo won ni won nilo awon ajihinrere agba sugbon o nira fun
awon alajo lati ri iwe iwolu gba (visa) lati wad a ijo sile. Awon ajihinrere
lati awon apa ibomiran ni orile ede Nigeria ni a nilo gidigidi.
AWON
IFITONILETI TI O WULO FUN AJERE OKAN
1.
O gbodo kun fun Emi Mimo (a)
Nitori bi ba ti njeri lodi si orisa won won le doju ija ko o nipa tie mi (b)
won le gbiyanju ogun lara re nipa tie mi.
2.
Wasu Kristi ki o si je ki Emi
Mimo ki o rin
·
Jeki igbagbo ki o dagba bi o ti
nwasu fun won.
·
Yago fun ijinyan ti ko wulo.
·
Afihan gbogbo re le ma le ran
iranyi lowo sugbon igbagbo ninu Emi Mimo le duro ki o si se iranwo nigba kugba.
3.
A nilo agbra Olorun.
·
O je ase fun awon onigbagbo.
·
O nmu ise ami ati ise iyanu wa bi
eniyan ba ti nwasu (Mark.16:15-18).
4.
A nilo adura ti o mu ina doko
Lk.18:1, Ps.102:17, Jakobu.5:16-20.
5.
A nilo igbeaye ti o dara ati
igbeaye mimo Heb.16:14.
6.
O gbodo dabobo oro Olorun
Heb.4:12, Ps.119:11, Ps.119:105, 130.
7.
O gbodo ni okan ikanu fun awon
okan to nsegbe Matt.14:14, Matt.9:38
8.
O gbodo feran Oluwa wa Jesu
Kristi John.4:12,15,21..
No comments:
Post a Comment