Tuesday, October 8, 2013

IPOLONGO GROUND OF TRUTH



GROUND OF TRUTH BIBLE INSTITUTE ADVERTISEMENT

Akanni:     Ore mi, mo ma ti ba d’oju e

Alade:       Ki lo de?

Akanni:     Ani won ti yo mi kuro lori pepe, ije boo! Won ni mi o mo’wasu wa, koda, won tun ni mi o mo Bibeli

Alade:       Ha! O dabi pe isoro wa jora o

Akanni:     Lona wo?

Alade:       Oluwa ran emi na nise iranse, sugbon mi o tile mo odo ti maa da orun’la si, se Olorun o ni yo emi na bayi?

Akowe: Owo yin lowa o, nitori Olorun ti gbe ile iwe Bibeli nla kan kale lati yanju gbogbo iru isoro yi; ile iwe na ni GROUND OF TRUTH BIBLE INSTITUTE

Nibi ti awon to fe la ipa ni iran won ti nbomi ogbon mu. Eyin Oludasile ijo, Eyin woli, Oluso aguntan, Olukoni ati Ajihinrere. Ema bo ni Ground of Truth Bible Institute ki e wa gba isiloju to n mu isiniye wa. Awon Oluko ti muse-muse won da muse-muse ni Oluwa ti pese sile nitori tire.

Rati wipe oto ni’pe, oto lepe, oto tun lope. Eni to ba mu’pe me’pe, iru won gan lanpe lope.                                                
AWON EKO WA
A ni eko nipa sise Adari ninu ijo (Advanced Christian Leadership)
A ni eko nipa ise iranse itusile (Deliverance Course)
Bakan na ni a ni eko nipa ibere ise iranse (Basic Ministerial Training)

IBI TI A WA
Lowo lowo a wa ni No1, Aboderin Street Agbaje Orita Challenge Ibadan.

Ni ilu Ogbomoso, awa Leba ile ise Adewuyi Bakery Olope marun-un Ogbomoso.

Ofe l’owo ikeko ni ile iwe wa, bakana lanko ni pelu ede Yoruba ati ede oyinbo.

Fun ibeere ati iwadi, o le pe awon ero ibanisoro yii. 08056008526, tabi 07031821386. Bakan na ni e le wo wa lori ero ayelukara ti Email:-groundoftruth2@yahoo.com Websit:- wa ni www.groundoftruth.net.ms
EMA BO NI GROUND OF TRUTH K’E KURO NIPO OPEE!!!

No comments: