AAGO ATI BAMUTISIMU
AFIHAN Idi ti Olorun fi ko wa jo papo fun eko yi ni
lati tun aye wa se, nitori Olorun ko le lo ayae ti a ko iti danwo. Ki Olorun to
le lo aye kan,
Oluwa yo ti sise aye re .
Gbenagbena
kan ko le lo gbogbo igi ti o ko wa lati sawmill, sugbon yo ko fa awon
kan kuro, yio ge awon kan kuro, papa ki se gbogbo patako to wonu yara atunse ni
yo farahan ni yara ifihan, sugbon ti o ba ti sise lori re ni yara atunse, yo
gbe wa si yara ifihan.
Nitorina, ohun ti o kan Olorun ga ni nipa eni ti yo ro ala okan
re fun awon eniyan re
Awon meji ni won di alafo yi nigba tiwon,
won duro niwaju oba won si so itumo ala won fun (Oba). Nje o mo pe Olorun ti
ise Oba awon oba ati Oluwa awon Oluwa ni ala, O ni ala si awon elese, si awon
to nse ijoba, si awon adari ijo ati olukuluku omo ijo kokan. ( Aini Olorun to
gaju ni, ‘tani yio ro’. Opo awon ti a daruko loke yi ni won je omo ijo kan tabi omiran.
A o se ayewo lati ninu aye awon eniyan
Olorun meji ti won ro ala ni igba aye won . eg
1). Josefu…………… Gen. 40: 1-13; 41:1-37
2). Danieli………….. Dan. 2:1-49 ; 4:5-37
![]() |
Gen. 40:1-13 Lati
inu awon ese Bibeli wonyi, a kiyesi pe aye omokunrin Heberu yi ni a fi pamo fun
idi ti ko han si oun gan tabi awon eniyan ti o wa ni ayika re, ki ise eyi
nikan, o ti se olooto si Olorun ni koko ati ni gbangba. Eyi lo mu ki omokunrin
ye fun ise miran ti orun ti pese aye re sile fun. E je ki a se ayewo iwe mimo
yi:
1). Ni ese ikarun, a kiyesi pe eniyan meji
la ala, bi o tile sepe ni ale kan
naa, sugbon ala otooto ati itumo otooto ni o wa fun won.
2). Ni ese ikefa ati ikejo ( 6 & 8 )
awon mejeji ni won banuje loripe ko si eniti yoo tumo ala won fun won.
Awon eniyan banuje loni nitori ti
tori a ko ri awon to kun oju osunwon lati tumo okan Olorun fun won.
3). Ohun miran ti a gbodo ko ninu itan aye
Josefu ko so itumo ala rere ni kan;
sugbon o tun tumo ala eyi ti o ni ijiya iku pelu.
Ti a ba
tun ka Gen.41: 1-14 a
o se akiyesi pe oba la ala kan
ati pe o nilo eniti ole tumo re.
Bakanna
Olorun se alaini awon eniti yio le se itumo awon ohun ti o wa ninu okan Olorun
fun
awon
eniyan Re, gege be a ti so tele pe Olorun ko ni lo ohun elo ti a ko danwo gege
bi irnse
fun ise
Re, eyi ni pe iyipada gbodo sele ninu aye enikeni ti yio ba tumo okan Olorun.
Iyipad
yi le
seese nigbati Olorun ba ba aye wa pade.
IPO
TI IGBE AYE JOSEFU WA
Ki o to dip e Josefu to le duro niwaju oba
Farao, bi o ti le je pe Josefu ni awon iwa amuye die eyi ti o le mu koju osuwon
fun ise naa, sugbon sibe, igbe aye re gbodo wa ni ibamu pelu eyi ti o le fun
ise naa.
Nigbana ni Farao ranse o sip e Josefu, nwon si yara muu jade
kuro ninu iho tubu, osi
fari re, o si paro aso re, o si to Farao wa.
Gen. 41:14/BSN/
Lati ibi ti aka yii a sakiyesi ohun merin to
sele si Josefu ki to le duro niwaju Farao bii
1). Won tete mu kuro ni kiakia kuro ninu
ogba ewon eyi to tumo sip e enikeni ti yoo ba duro niwaju Oluwa lati so itumo
okan Re ko gbodo wa ninu ise ese kankan.
2). O fa irungbon re: eyi fi han pe apeere
ogba ewon ni ati mu kuro, irun
re ni ati yipada awon to mo tele le nu o ya pe irun esu to se si ori re ko si nibe.
3). O yi aso re pada: O ko le ba Olorun pade
ki o situn wa bakanna, imura re gbodo yi pada, ti o ba je ogbe ti o jin ni
osele ninu aye re agbodo ri apa re lode ara re, ki o to le duro lati tumo okan
Olorun, imura re gbodo yi pada.
4). O wa si odo Farao: Josefu ko sa lo si
odo awon obi re, oga re tabi awon ore re kankan,
sugbon o lo si odo oba eniti o npe. O gbodo wa ni arowoto Olorun lati se ohun
ti o ni lokan fun o.
Dan
2:1-49 Leyin igba ti a ti se agbeyewo igbe aye Josefu, o se Pataki lati tun se agbeyewo
aye
Daniel bakannaa, nitori pea won iranse Olorun yi wonyi ni igbe aye ti o jora
won bii.
A). Won je Heberu
B). Won wa ni ile ajoji
C). Olorun ma nbe won wo nipase ala ati iran.
D). Awon mejeji ni o ni oore ofe lati tumo
ala A.B.B.L
Iru eru
wuwo ti owa ninu okan Olorun, kosi enikan ti o je aworan, pidan-pidn ati
alafose ti o
le so
tumo re. ( Dan. 2: 27) Yato si awon eniyan Re ti won ni amuye ti orun gbe kale.
Gbgbi awon ni ti Olorun yio fi okan re han
gbodo ni awon iwa amuye wonyi:
1). Eni ti o ni ipinnu lati yato ( Dan. 1:8)
2). Eni ti ko fi ara re han pe oun je nkan (
Dan. 2:2)
3). Eni ti o le ya rara re soto lati w oju
Olorun ( Da. 2:17-19)
4). Eni ti o le gba aye elomiran la. ( Dan.
2: 36, 49)
6). Eni ti ibugbe re ki ise pelu eran ara (
Dan.2:11)
7). Eni ti o ni Emi Olorun mimo ( Dan. 4: 18)
Eyi ni ohun ti Olorun n wa, kiise pe kosi awon
eniyan ti won le fe lati tumo ala, sugbon
awon ti
won le kun oju osuwon ti Olorun gbe kale ni o sowon.
Idi niyi
ti Olorun fi mu o wa sibi ki o ba le sise lori re ninu iyara isise ( Workshop)
Re, ki o to
se
afihan re ninu iyara iseloso ( Showroom) eyi tiise ori aga iwasu. Se iwo yio mu aye re wa
ni
arowoto. Nje o ti mura tan lati se gbogbo atunse awon ohun ti o lodi ninu aye re ti Oluwa
yio ma
fi han fun o? Eje ki agbadura.
![]() |
AAGO NAA
NIgba ti
iya awon awon omo Sebedi meji wa sodo Jesu ti o si nbebe jijoko ni owo otun ati
owo osi
fun awon omo re ni ijoba Re, igbayi ni Jesu mu ro yi wa:
“Sugbon
Jesus dahun, o si wipe, Enyin ko mo
ohun
ti enyin nbere. Enyin le mu ninu ago
ti Emi o mu, ati ki a fi baptismu ti a o fi
baptismu
mi
baptisi nyin? Nwonwi fun pe, Awa le see” Matt 20:22 (B.S.N)
Oro ti a npe ni aago a so ni aadojo igba
ninu Bibeli, a le ma le se agbeyewo gbogbo re.
Sugbon orisi marun ago ti ose Pataki julo
ninu Bibeli ni a o se agbeyewo re gege bi Olorun yio se ran wa lowo.
(1). Ago
aisedeede
(2). Aago
iponju
(3). Aago
ibinu Eru ati idajo
(4). Aogo
onje ale Oluwa
(5). Aago
ibukun.
AAGO AISEDEEDE
Nitorina nigbati Jesu n baa won omo Sebede
nsoro, o nso ni pato lori ago akoko Jesu mo pe oun nikan ni Oun le mu iru ago
be ( John18:11)
TANI
AISEDEEDE?
Nigbati Lusiferi so ipe re nu ni orun, o
wa pada di satani ati esu nitori ti a ri aisedeede ninu
re, Olorun pa ogo ti o wa ni ara re re, lese kanna ni o si di okunkun ( Ezek.
28:13-15, ISa. 14:12-17)
ISUBU ENIYAN
Olorun da eniyan, Olorun da ni pipe titi di
igbati ogbeni aisedeede fi wole wa sinu ogba Edeni ( Gen. 3:1)
Ohun ti esu polowo fun Obinrin naa ni
ominira, eyi ni pe ko ni nilo Olorun mo
lati wa ma be wo sugbon ohun ni yio ma se idajo ara re fun ra re.
Ohun gbogbo ti Obinrin na ti je ni awon ohun
ti esu npolowo fun wipe:
1). Oju
yin yio la
2). Eyin
yio dabi Olorun
3). Eyin
yio mo rere ati buburu
Bibeli wipe” Nigbati Obinrin naa ri pe igina
dara fun jije” Gbogbo igi ti oku nibe se
won ko dara fun jijeni? Esu ko fi igi miran han bi ko se igi ti Olorun sope “ E
ko gbodo je ninu re”
IDANWO META
NINU ISUBU ENIYAN
1). Odara
fun jije ( ifekufe ara)
2). Odara
fun oju ( ifekufe oju)
3). Ama
mu nig bon ( irera aye)
Bayi ni gbogbo iran eniyan se subu ti won si fi
owo ara won yonda aye yi ati aye won fun satani 2Pet. 2:19, John 8: 34
![]() |
|||
![]() |
|||
Nitori naa aye okunkun yi ni o nran awon
eniyan sinu ina orun apaadi lati igba isubu eniyan.
Idi niyi ti Jesu fi wa lati mu igbe aye
okunkun kuro, sugbon eyi yio rorun fun nipa fifa aisedeede jade kuro eyi ti ise
igbe aye okunkun. Eyi ni aago ti Jesu mu lori agbelebu nipase iku re. Ps. 116:
13, Matt 26: 39-42, Jn 19:28-30 Jn 18:11, Heb 2:14 Eyi imuse ira Johannu OLufeninu iwe Ifihan 5: 1-7 nibi ti o ti je
pe Jesu nikan lole tu edidi iparun aye. 1Kor. 15: 54-57
AAGO IPONJU
Eyi aago to Jesu so fun iyaawon omo Sebede
pe won o mu nigbati o ba ya.
Eyin o mu ninu agomi, ati
ninu baptisimu,
ti a o fi baptisi mi lia o
si fi baptisi nyin:
Sugbon lati joko li owo
otun ati owo osi mi ki ise
Ti emi lati fi funmi,
bikosepe fun kiki awon eniti a ti
pese re sile fun lati odo Baba mi wa. Matt.
20:23
kii se awon sebede nikan nni o mu aago yi
sugbon Aposteli ati Kristenni akoko.
Ohun kan
nip e, iponju ati inunibini ni aini pe oti ba Oluwa pade nitooto, tori Jesu so
be ki o to kuro ninu aye. 1 Johannu 3:13
& 14
Bi aye ba korira nyin, e mo
pe, o ti korira mi saju nyin.
Ibasepe enyin ise ti aiye,
aye iba fe awon tire: sugbon
Nitori enyin ise ti aiye,
sugbon emi ti yan nyin kuro
Ninu aye, nitori eyi li
aiya se korira nyin. Johannu 15:18-19
Nigba gbogbo ni aago iponju ati inunibini ma
nwa si oju ona wa bi a se n tele Jesu Oluwa.
ti aago yi ba rekoja aye re, o nilo kigbe,
nitori ohun ti dimu ki se Ojulowo 1Peter 2:21-26,
ITess. 2:1-3, Fillipi 1:28-29, Jakobu 1:2-3
AGO IRUNU
ERU ATI IDAJO
Eyi ni aago okora emi ni
janu, ijiya ati ibawi eyi ti Olorun fun gbogbo awon ti o se ati elese
KINI
ESE
Ese ni riru ofin be si ni gbogbo riru ofin
ni yoo mu ijiya wa. Isa. 51:17-23, Jer. 49:12,
Ifihan 14:10
AWON ILU TI O MU
AAGO NAA
1). Sodomu
ati Gomorah ( Gen. 19: 24-25)
2). Babiloni ( Ifihan 18: 1-8)
3). Egipti ( Exo. 12:29-30)
4). Samria ( Awon Oba Keji 17:
1-8)
5). Jerusalemu ( II Kronika 26: 15-21)
ENIYAN KO OKAN TO MU AAGO NAA
1. Farao
( Ezek. 30:
20-24)
2. Nebukadnesari (Daniel 4:28-30)
3). Herodu ( Ise
Aposteli 12:21-24)
4). Nadabu
ati Abihu (Lev. 10:1-3)
5). Miriamu
ati Aaroni (Numeri 12: 1-15)
6). Eli
ati awon omo re (1sam. 3:11-14, 4:10, 11, 18).
AAGO
ONJE ALE OLUWA
Eyi ni aago Oluwa eyi to gbekele nigbati o fe lo si ibi agbelebu.
Matt. 26:26-28, 1kro. 10:21.
1 kor. 11:23-26.
![]() |
1). Awon
ti won ko iti ba Oluwa pade
2. Awon
ti won ko iti se iribomi ti o tona ninu odo
3. Awon
ti o si nyan odi
4). Awon
alaya pupo ati oloko pupo
5). Awon
ti ko iti se atunse ona won ti o lodi
![]() |
AGO IBUKUN
Eyi ni aago imuse ileri ati aago ise rere.
Orin Dafidi 23:5, 16:5 Gbogbo onigbagbo gbodo mo eyi pe, a ko le mu aago eyi ti
a ko ba koko mu awon eyi ti a koko so
loke.
![]() |
ORO AKOKOSO
Iribo ni nkan lara igbese ti o ma nje ki
eniyan ye fun orun,
Gege be Mk. 16:16 ti so pe Eniti o ba gbagbo,
Ti a ba si baptisi re yi o la, sugbon eniti
ko ba gbagbo yio jebi.
Ninu ror to so lati inu Bibeli yi, a se
akiyesi pe lati gbagbo ni Igbese akoko ati lati se baptisi ni igbese keji,
sugbon awon eniyan ti o si to lode oni nitorina ti o ba si to ni ona kan tabi
omiran o fi han gbangba pe iwo ko ti ye fun orun ayafi igbati o ba tele eto
Olorun yi.
GBAGBO ATI GBALA
Awon oro meji wonyi da bi eyi to ru ni loju,
nitoripe ti a bawo nipa ti ara, won ko le lo papo, sugbon nipa ti Emi won dabi
tokotaya, nitori idi eyi awon mejeji nsise papo “ gbagbo ki o si nni igbala”
nitori idi eyi a o wo won ni okan-kan nisoki-soki.
Lehin ti a ba gbagbo ti a si ni igbala, ohun
ti o kan ni
ohun ti a pe ni baptisimu.
Oro ti a pe ni baptisimu yi wa lati inu ede Giriki. A si n pe ni
Baptizo eyi ti o tunmo si pe ki a rin ohun kan bo
inu omiran titi ti akofi niri mo. Fun apere omi, iwe ile ati bee bee lo.
KINI IDI BAMUTISIMU
a). O
je asepe tabi asepari ise igbala wa ( marku 16:16)
b). O
j ease Jesu Oluwa ( Matt. 28:19)
c). O
wa fun eri okan rere nipa Olorun ( I Pet. 3: 21)
APERE BAMUTISIMU TO KO DARA
1).
Sisami agbelebu niwaju ori
2). Fifi
omi won eniyan lori
3). Sisare
koja labe aso
funfun tabi aso pupa
4). Riri
eniyan bo inu adagun omi ( lehinkule soosi)
5). Sisare
koja labe
mariwo ope.
BAMITISIMU TI O DARA
Baptisimu ti o dara ni eyi ti a se ni ona ti
o ba Bibeli mu tabi ti o ni gbongbo re ninu Bibeli, eyi ni baptisimu inu odo ti
o nsan. Fun apere
1). Johannu
baptisi awon eniyan ninu odo ( John 3:
22-24, Marku. 1: 4-5)
2). Jesu
wa se baptisi ninu odo Jordani ( Marku 1:9-10)
3). Iwefa
ara Etiopia se baptisi ninu odo to n san ( ISe Awon Aposteli 8:35-39)







No comments:
Post a Comment