SUGGESTED TOPICS OF THESIS FOR 200LEVEL STUDENTS
1. IJAKADI FUN AGBARA NINU IJO TI ODE ONI.
2. ISOTE KORAH: APERE ASAAJU TI KO DARA.
3. IDAGBA ATI AWON ASISE MUSULUMI.
4. IPA TI EKO IJO NKO NINU IJO ODE ONI.
5. LATI INU IJO LO SINU ORUNAPADI.
6. IGBE AYE IRANSE: IPILE RERE FUN ISE IRANSE.
7. OHUN TO NSE IKUPA ISOJI NI ILE WA.
8. OKUNFA EDE AIYEDE NINU IJO.
9. ASISE BALAAMU NINU IJO TI ODE ONI.
10. ITAN IJO LATI MAJEMU LAILAI TITI DI AKOKO YI.
11. IDILE; IPILE PIPE FUN ISE IRANSE.
12. IDAGBA ATI LAISIGBO IJO C.A.C.
13. WAHALA AWON WOLI NINU IJO ODE ONI
14. EMI MIMO: IRANWO FUN IPILE IGBEYAWO KRISTENI
15. AWON IPENIJA AWON WOOLI IGBANI
16. AWON ILAKOJA BIBERE ISE-IRANSE IJO
17. IGBEYAWO LAISI EKUN
18. WAHALA OSELU NINU IJO ODE ONI
19. AISAN ISE IJERE OKAN NINU IJO ODE ONI.
20. AWON IPENIJA ISE IRANSE ABULE
21. ARIWO EKUN ATI TI AYO NINU IJO ODE ONI
22. THE PURPOSE AND PURSUIT OF A CORRECT PREACHER.
23. THE CAPTIVITY OF THE CHOSEN GENERATION
24. BIBLICAL OFFERING AND IT’S IMPLICATION IN THE CONTEMPORARY CHURCH
25. THE EFFECT OF CHURCH EDUCATION IN THE TODAY’S CHURCH.
26. MINISTER'S LIFE: WHY REVIVAL TARRIED
INSTRUCTION: Please write your name on the chosen topic that you can write on your own without been helped and write an official letter to the School’s Board of Studies to request for the topic officially.
Please submit your letter on or before 14th July 2017 unfailingly.
ITONI: Jowo ko oruko siwaju akori ti o le da ko lai ran e lowo, ki o si ko iwe si igbimo to nsakoso eko (Board of Studies) lati beere fun akori na. Jowo te iwe re, ki o si fi sile ki o to di ojo tabi ni ojo kerinla osu keje odun yi.
____________________
For The Board of Studies
No comments:
Post a Comment