IGBE AYE ATI AWON EKO KRISTIANI
A few o bi Jesu se gbe
bi eniyan. Awon ohun
1.
Ifara tabi oro aso siwaju
2.
Ibi Joahnu onitebomi
Sise
asotele
3.
Ibi Jesu
a.
Ikede tabi iritonileti
b.
Ibi olugbala
4.
Titeowo gba omo naa
a.
Awon daran daran fori bale fun
b.
Ti a ki kabo lati odo awon enimimo
isreali
c.
Ti a se awari ti a si fori bale fun lati
odo
d.
Awon amoye
Ti
a gbogun ti lati odo oba Isreali
5.
Awon mo lebi Herodu
6.
Jesu Kristi ni gba to wa lomo de
a.
Titedo tabi gbigbe ni Nasareti
b.
Abewo akoko si Jerusalem
c.
Awon odun mejidinlogun ni odun idakekeje
7.
Ise iranse Jonah onitebomi
8.
Iri bomi Jesu
Oun
ti iri bomi Jesu tumosi
9.
Idanwo Jesu Kristi
10.
Awon omo lehin akoko
11.
Ise iyanu akoko ti Jesu se
12.
Awon ise iranse Jesun se
a.
Awon koko gbongi ti be ninu ise iranse
re
b.
Aase ti waasu re
13.
Iwasu ni ori o ko
14.
Awon eko Kristi nipa owe
15.
Won tako ise iranse Jesu Kristi
16.
Messiah ti a ko sile so asotele rupa iku
re
17.
Ori oke iralapada
a.
Gigba dura nipa isoro agbelebu
b.
Imole orun lori agbelebu
c.
Ibere meta to soro dahun
18.
Akoko to wa larin Jesu iwa saye jesu
akoko ati ipada bo re lekeji
19.
Isin ounje ale Oluwa ti a mo si idapo
20.
Oro idagbere ti Jesu Kristi
21.
Ipade adura to gbeyin
22.
Amun Jesu Kristi
a.
Ikerora ninu ogba Gestimoni
23.
Gbongan igbe jo ati idalebi Kristi
A.
Gbongan idajo Jesu nipa oro esin
a.
Eko eke
b.
Ewon tabi agbedo
c.
Oro odi
B.
Igbejo nipa ti oro ilu
24.
Ikan mo agbelebu Jesu Kristi
a.
Kristi ni ori agbelebu
b.
Awon eniyan to ba nitosi agbelebu
c.
Krisiti lehi agbelebu
Ohun
ti agbelebu tumosi
25.
Otito ti ajinde
a.
Akosile nipa ajinde
b.
Igoke re orun Jesu Kristi
Oro akoso agbodo loye re pe opolopo asotele loti
waye nipa Jesu Kristi ko to di wipe abi Jesu lati odo awon woli ninu majemu
lailai. Opolopo odun losi ti kojalo to dabi pea won asotele ti awon woli majemu
lailai yi so pe ko ni was si muise.
Woli
Isaiah so asotele nipa nbi Jesu be na ru ogo oro awon Woli ti inu majemu lailai
titi ti o fi de ori woli majemu lailai
ti o gbeyin ti a mo si Malaki
Bi a se de inu iwe majemu titun be na ni asotele
nipa Jesu Kristi bere sini se o sib ere pelu ibi Joahnu onitebomi. Luku 1:1-25,
57,80
SISE
ASOTELE
A
le pe asotele woli Malaki gege oro idagbere ti majemu lailai nitori lehi awon
oro woli Malaki odidi irinwo odun ni a ko gbo ohun woli Kankan ni Isreali.
Awon
Woli won woli majemu lailai won je ise iranse wonl ni pipe ohun ti a kun i ki
awon ori le de ma kiyesi oro won fun imuse awon asotele gbogbo ti a ti so ni
majemu lailai.
Ni
akoko yin i awon eniyan wonaa fun imuse ibi olugbala ti yio wa ninu ileri jije
ati ileri jije oba ati ipo ibi re se lara awon asotele toti saju ninu majemu
lailai ni eyi ti o wa lati enu woli laloli Isaiah wipe emi Elijah yin o wa lati
pese ona sile fun ojo nla dide Oluwa. Isaiah 40:3-4.
Bi
a se wo inu majemu titu ni a kiye si pe ibi Jesu bere pelu ikede idoli
alagbara, ti Emi mimo yio ku inu re lati mu oyu wa ti yio si pese ona sile fun
Oluwa niti Luku 1:11-17
Lehin
akoko idakejeje fun irin woo dun orun si sile fun ikede angeli Gebureli nipa
eni kan ti yio wa se iranse fun Isreali “ni Emi ati agbara Elijan” eni naa ni
Johanu onitebomi eni ti a kede ibi re fun (Zakaraya agba alufa) ati Elizabeth
aya re ti o ya agan Joahun onitebomi yi ni a so pe yio je “iranse” lati pese
ona sile fun Oluwa nitori oun ni yio lo saaju olugabala lati lo ma kede iwasaye
Jesu ati lati pese ona sile fun-un Oluwa bi Johanu se se yin i awon ipa tire
yio ma di igbagbe.
IBI
JESU KRISTI
Ibi Kristi Jesu
Matiu 1:18-2, Luku 2:1-4 Mika5:2
IKEDE
IBI JESU
Olorun ti pase re pe Jesu Kristi ni
a ma bi ni pase Wundia obinrin nitori ki omo naa le gbe igbe aiye re bi eniyan.
Gen 3:15, Galatia 4:14.
Maria
okan lara awon Wundia Isreali ni a fun lokan ninu ore ofe nla nla yi lati je
iya omo Olorun naa sun meta lehin ti Olorun kede Johanu Onitebomi, angelen naa
to fi to Mari leti “pe oun ni yio je iya olurapada araye, nitori idi eyi pe emi
Olorun ho siji bo o nitori ti omo naa mo ba je omo eniyan nikan sugbon ki o le
je omo Olorun.
ADURA OLUWA JEKI AANU PADE MI
Pelu Luku 1:30-35
Maria
ni eni ti o ri oju rere Olorun lati je iya olugbala araye eniti awon obinrin
Juu ti foju sona fun saju isele yi. Maria ti je afesona fun eni iwa bi Olorun
kan ti oruko je Josefu nigba ti Josefu wa mop e Maria ti loyun oun ronu lati ko
sile ni ikoko eyi ti on mu ki Olorun ki ran angeli sip e omo ti o wa ninu re pe
oyun Emi mimo ni ati wipe ibi Wundia ni a ma bi omo naa ati pe orrun omo naa
ni a mo pe ni Jesu ti o tunmosi
“Olugbala araye” ati pe o tun mop e oruko re ni immanueli ti o tun mo si pe
olurun ti fi ara re han fun eniyan ni oro ti ko ti sele ri “Immanueli ni tumosi
olurun wa pelu wa” 1John 1:14, 2Kroni5:19. Gbogbo awon ikan wonyi hun waye lati
fi idi jije eniyan Jesu Kristi mule ohun ti a pe ni eko nipa ti ara nip e Jesu Kristi waye nipa se eniyan Jesun wan i iririara eran ara ko mo ba si
awawi ninu eniyan, gbogbo ohun ti a le pen i iya ni ati je Jesu ,Jesu naa ti je
iru re ni inu ara re ko to goke re orun. Luku 2:1-7 nigbati a fe bi Jesu ni
ojo won ni ase wa lati odo ijoba Romu pe ki awon omo Juu ma lo si ile ibi won
si agbo ile won fun iforukosile ti ikan eniyan ase yi ni o faye gba pe ki a lo
bi Jesu ni ibi ti awon woli lailai nit i so. “Betteliemu” Mika5:2 ki a le fi
aye fun iru omo Dafidi luku 2:1-9 bi tan ti Jesu ba Dafidi tan je imuse ileri ti
Olorun se fun Dafidi pe oba alade koru koro ni ile re 2Sam 7:16 Mattiu 1:21,
Isaiah 11:1, Luku 1:32-33, Isaiah 9:6-7. Ninu awon ese bibeli tti a ko soke yi
olugbala dide lati inu idile Dafidi ni akoko ti o dabi pe ati gbojun fo ileri
yi ru ile Dafidi wipe opa ase koni kuro ni ile Dafidi igba yi ni olugbala araye
lalehun lati odo eni ti a o le ro ati Joseph omo gbengbena kapeta ati Maria
wudia koja ogbon ori eniyan at iyanu ni kukute ti o dabi ki gbongbon re gbo
orun onu ti ewe reso jade bi arabati gbongbn re so jade ti o wa di afani si
gboggbo mutumu wa
TI TEWO GBA OMO NAA
Mattiu 2:1-end Luku 2:1- Edu
A. AWON DARAB FORI BALEFUN
Luku 2:8-20
Awon daran daran fori bale fun awon ni a
fun ni ore ofe lati se ikede Jesu Krisiti ati lati kede pea bi Kristi olugbala
ni Bethelemu Judia ati lati kede pe ati bi olugbala ni Bethelemu judia awon won
si ore ofe lati gbo orin ohun orin awon Angeli Olorun ti won korin iyin si
Olorun nipa ibi Jesu Olugbala araye eni ti yio fi ogo Olorun han fun ati fun
Alafia fun awon eniyan ati ife inu rere si eniyan, lehin ti won ti ri omo naa
Jesu Krisiti ni ibuje eran won si bere sini se ikede irohin ayo naa pe ireti
ogo ti Isreali reti ti de inu aye
B.
TI
A KI KABO LATI ODO AWON ENI MIMO
Isreali Luku 2:4-31 nigbati abi Jesu to
di omo ojo mejo ako Jesu nila gege bi ofin inu se Mose nitori eyi Jesu Kristi
di okan ni nu eni majemu Olorun Heberu 8:7-12
A
gbe Jesu losi tempili gege bi akobi ninu malebi naa a si yaa sii mimooo fun
Olorun. Fun oogoro ogorun odun ni awon eni mimo ti wo naa pelu suuru fun ibi
Messiah naa opolopo odun si ti koja ti ileri yi ko di mimu se, sugbon bayi eni
mimo kan wa ti o lojo lori ti a n pe ni Simonii eni tie mi ti so fun pe nipa
irohin rere pe koni ri iku ko to ri Kristi ti se olugbala araye eni Olorun si dari re si
tempili. Omo ti won ya ni were
Simoni
yi kun fun ayo nigbati awon obi Jesu gbe Jesu wa nigbati o fi oju ri Jesu Kristi ti o sig be
olugbala araye le apa re nigbayi afi igbayi naa ni Hanah agba woli naa to hun
naa ri Jesu eni to se ikede Jesu fun awon olufokan sin Juu ti won ngbe ni
tempili lojojumo fun iwo naa fun igbala oluwa. Luku 2:25-38. Wura tumosi oba turari ise woli totumo okan
Olurun
C.
TI
A SE AWARI TI A SI FO RI BALEFUN LATI ODO AWON AMOYE
Matiu 2:1-12 Awon amoye naa ni a npe ni
“Maggic” ti o tumosi “oni mo kefferi” tabi awon amoye Tani awon amoye? Kinni jeta? Maggic or Awon Amoye
Nigbati a bi Jesu ni
Betilemu ti Judia awon amoye wa lati ila oorun lati foribale fun ojialo tumosi ohun ti a fi jona wipe aiye
re ni yo fi nibo olifi lati lo, wo isubu Jerusalam opo ti mu awon eniyan
losi ibi asale lati duro de ami omo eniyan gege be Danieli ti sotele asotele
re. Nitori naa nigbati awon amoye kede oba tit u kan ti yi oo je olugbala araye
logan ni Herodu gbero lati pa sugbon angeli Olorun yo si awon amoye naa la o si
so fun won ki won mo pada sodo oba Herodu mo.
Olorun
dara lopolopo nitori bi o se ran angeli si awon amoye beeni oran won si awon
ibi Jesu la lati owo oba buburu ti o wa emi Jesu lati pa nitori eyi, opolopo
omokunrin omo Juu lati odun meji si isale lopa ati le mu ki asotele Jeremiah
31:15 ki o was i imuse Mattiu 2:16-18
Awon
omo Bethelemu ti Herodu unpayi koje ikankan fun nitori ehana oba ni ti pa iyawo
arra re opolopo omo re loti seku pa opolopo awon ore re loti pa pelu.
Oba
Herodu mop e awon eniyan yo yo tabi dun inu si iku oun nitori naa ogoro awon
omo Juuni o gbe si atimole ti o si pase ni ikoko wipe ti won ba gbo pe oun ku
gbogbo won ni ki e pa ti awon eniyan ko ba sokun fun oun won yio so kun fun
awon ti won ti mo le awon eniyan yi o ridi lati sokun fun awon eniyan won ati
pe eyi yio fa ibanuje la fun won ti gbogobo eniyan yio fi ma sofo, sugbon ase
yi ni ako muse.
OBA
ISREALI GBOGUN TI JESIU
Ni akoko ti abi Jesu,
Herodu ti o buru jai ni o wa lori oye nigba naa (Idi ti o fi buru ni o je apa
iran Esau ati apakan isreali) awon alase ile Romu lofi je oba tipatipa le won
lori
Awon Juu korira re lopolopo won ko si gbape oba awon
ni rara oba yii buru to be ti awon eniyan gbero lati pa tabi ki awon ro loye
nitori ikorira naa po opoloopo ninu awon opuru won yi ti opolopo awon eniyan lo
si ori oke olifi lati lo wo isubu Jerusalemu opo ti mu awon eniyan losi ibi
asale lati duro de ami omo eniyan gege bi Danieli ti asotele re. Nitori naa
nigbati awon amoye kede oba ti tu kan ti yio je olugbala araye logan ni Herodu
gbero lati pa sugbon angeli Olorun o si awon amoye naa la o si so fun won ki won
mo pade sodo oba Herodo mo.
Olorun dara lopolopo nitori bi o se ran angeli si
awon amoye beni oran won si awon obi Jesu naa.Matiu 2:2:12-15 eyi lomu ki a gba
emi Jesu lati pa lowo oba buburu ti o wa emi Jesu lati pa nitori eyi, opolopo
omokunmrin omo Juu lati odun Meji si
isale lopa lati le mu ki asotele Jeremiah 31:15 ki o was i imuse Matiu 2:16-18.
Awon
omo Bethelemu tii Herodu unpa yi ko je ikankan fun nitori ehana oba ni o ti pa
iyawon ara re opolopo omo re loti seku pa opololopo awon ore re loti pa pelu
Oba Herodu mope awon eniyan yo yo
tabi dun inu si iku oun nitori na ogoro awon omo Juu ni o gbe si atimole ti o
si pase ni ikoko wipe ti won ba gbo pe oun ku gbogbo won ni ki e pa ti awon
eniyan ko ba sokun fun oun won yio so kun fun awon ti won ti mole awon eniyan
yi o ridi lati sokun fun awon eniyan won ati pe yio fi ma sofo, sugbon ase ni
ako muse.
IBEWOO
AKOKO SI JERUSALEMU
Luku 2:42-52
Luku nikan ni o ko irohin yi larin awon ako irohin
ihinnrere won yi oun nikan ni o ko irohin nipa kekere Jesu ati iseda eniyan
Jesu o se afihan Jesu bi Jesu sedagba bi eniyan bi o tile je pe omo Olorun ni.
Luku jeki a mop e nigbati Jesu pe
omo odun mejila Jesu baa won obi re losi ajo Jerusalemu fun iranti re lo do dun
nigbati won pada bo won padanu Jesu nigba ti won ti wa won ri Jesu ni tempili
ni ibi ti o ti bawon jiroro oro. Olorun nipa oro ofin nigbati won ri, o fi
iyanu han o wipe “ese ti e fi wa mikiri” hunk ole sa ise ise baba mi.
Awon
obi Jesu koni oye re pe woon ti omo ti oye re jut i won lo idi Pataki ti won fi
se akosile isele eyi ni lati ko wa leko wipe ye pe omo Olorun ni ohun o si
kiyesi idi ati ero Pataki ti Olorun fi ran ohun wa si aiye.
AWON
ODUN IDAKE RORO
Awon
odun mejidinlogun ti o wa larin odun
mejila ti Jesu se abewo si Jerusalemu ati akoko ti Jesu je omo ogbon odun ti
Jesu bere ise iranse re o lo awon odun won ni akata Maria ati Josefu awon obi
re ni Nasareti niile Josefu ati Maria yi ni ibe lo ti se ise gbena gbena re
gege bi Marku 6:3 ti so lehin iku Josefu Jesu se ise gbenagbena fun iya re lati
fi ran iya re lowo.
Jesu
fi apere rere lele fun wa naa lati tele ni Nasareti ni Jesu ti dagba o po ninu
Ogbon o si rri oju rere lodo eniyan ati lodo Olorun Jesus i lo akoko re lati
duro de igba afihan fun ise iranse re Jerusalemu.
ISE
IRANSE JOHANU ONITEBOMI APA KINNI
Mattiu 3:1-12 Luku 3:1-20
Nigbati Jesu wa ni Nasareti ti o duro de igba afihan
re Emi Olorun dari Johanu onitebomi lati lo bere ise iranse re gege bi eni ti a
ran gege bi eni ti a ran saju Jesu Kristi lati lo tu ona oluwa
se Isaiah 40:3-4
Awon oro Johanu kun fun awon liana ti o se afihan
ise iranse Johanu saju ise iranse Jesu Kristi itoni ji ati ifitoni leti ati
iran ni leti nipa ti Kristi ti o mbo “ohun eni ti kigbe ni iju” etu ona Oluwa
se ki e si mu ona re to”
Johanu
jeki a mop e iranse ni ohun ohun ti o kede nipa Messiah ti won reti pe o freed
ise ti a gbele Johanu lowo ise ti a ran lati lo se afihan Messiah ti awon
eniyan ti reti ti tio yio wa lati Nazareti ti galilee ti yio je Olugbala araye.
Gbogbo
eniyan lo bu ola fun Johanu onitebomi ni gbogbo ile naa eri re je eyi to fi di
Jesu Kristi mule ti o si fii idi ise iranse Jesu mule Matiu 21:23-27
ISE
IRANSE JOHANNU ONITEBOMI APA KEJI
Gbogbo awon
ihinrere alafijo ni won ko oro nipa ise iranse Johanu onitebomi ti won si ko
oro nipa amuje Johannu gege bi eru ti a ran saju Jesu krisiti die ni awon iwa
amuye Johanu ni a fe menu bay i:
1.
Iwaasu re duro lori ironupiwada awon
elese Mattiu 3:1-2
2.
“o se apejuwe ara re gege bei ohun eru
ti kigbe ni iju” Matiu 3:3
3.
O wa lati tun ona oluwa se Matiu 3:3
4.
O je oniwasu ti o ni gboya gbogbo awon
elesin, awon oloselu, awon somori ati awon gbanjumo tabi awon otokulu ilu ni o
ba soro ironupiwada mattiu 3:7
5.
Iwaasu re duro lori idajo Olorun to mbo
nti koo pe mo Mattiu 3:7-8
6.
O mo gbangba pe Jesu ki se egbe oun
Matiu 3:11
7.
Ti rele ti rele lo fi be Jesu wipe oun
ko ye lati se iri bomi fun Mattiu 3:13-15
8.
Johanu se afihan Jesu gege bi odo
aguntan Olorun ti o ko ese araye lo john 1:29
9.
Johanu se afi han Jesu pelu eri ati
idaniloju Matiu 3:16-17, John 1”31-36 eri ye ni wipe enikeni ti Emi ba so le
ori re oun na ni Jesu Kristi
10.
Johanu onitebomi da ipe re mo Mattiu
3:1-3
ISE
IRANSE JESU KRISITI
Ni geere ti Jesu pe omo ogbon odun ti ase iri bomi fun ni
o lo gba awe ogoji ojo ni inu iju gege bi a ti mura sile gege ibere ise iranse
re
A ko ri ise iranse re ni ironupiwada nitori ijoba orun ku
sidede eyi pada kki e si gba ihinrere gbo Marku 1:15 gege bi ironupiwada se se
Pataki ni igba naa ni o si pari dan ni akoko wa yi
AWON IDI TI ENIYAN SE NILO
IRONUPIWADA
1.
Nitori ese lo ya eniyan nipa pelu Olorun
ninu ogba Edeni Gen 3:7-8
2.
Gbogbo igbadun inu ogba Eden lo bo sonu
mo eniyan iran eniyan lowo nitori ese Gen 3:22-24
3.
Ese ti mu ki iran eniyan ti kun naa ogo
Olorun Romu3:3
4.
Ani lo lati ronupiwada nitori iku ni ere
ese Romu 6:23
5.
Nitori Olorun je mimo iran eniyan si je
elese ti a ba fe je mimo agboodo ro lufiti 11:44 piwada
6.
Nitori eniyan gbodo di atunbi lati jogun
iye ainipekun John 3:3
7.
Nitori ninu ese ni a loyun eniyan ninu
aisedede ni a si wo dagba. Orindafidi 51:5
8.
Tori eyi ti abi ninu ara, ara nise John
3:6
9.
Nitori Olorun ki gbo adura elese. John
9:31
10.
Nitori orun apadi ni elese unlo . Rev
21:8
1. Mattiu
2: Luku 1:5
2. Mattiu
2:22
3. Mattiu
14:1-11 Marku 6:4 Luku 3:1-13:31:23:7-12
4. Marku
6:21-28
5. A.A
12:1-2 A.A 18-23
6. A.A
25:13 26,26-32
7. A.A
25:13 26:27
8. A.A 24:24
HOW
THEY RULED
HEROD 3
(ANTIPAS)
HEROD 4
(PHILLIPI 1)
HEROD 5
(PHILLIPI II)
HEROOD 6
(AGRIPPA1)
HEROD 7 (AGRIPPA
II)
ALAYE
NIPA MOLEBI HERODU
Antipa to wa lo ke patapata ye ni baba nla won odo
re ni won tii se wa Anti pata lo tele. Antipata bi omo marun;
1.
Salome
2.
Ferorasi
3.
Josefun
4.
Omo re Herodu akoko
5.
Fasa ni abi gbehin
Herodu agba fe iyawo marun ninu iya wo marun:
1.
Iyawo akoko ti anpe oruko re ni Dorisa
2.
Iyawo keji Mariamu ati Makabis
3.
Iyawo Keta Mariamu ti Betusemu
4.
Iyawo kerin Mateki
5.
Iyawo karun ki lo kapura
a.
Iyawo akoko Dorisa to je iyale patapata
bi omo kan
b.
Iyawo keji Mariamu makabisi bi omo meji
oruko won Alesadaru ati Alisobulosi
c.
Iyawo keta ti o je Mariamu Betusimu o bi
omo kan oruko re ni Fillipi akoko Herodu kerin ]
d.
Iyawo kerin ti a npe ni Mateki o bi omo
meji tire ni oruko won niyi Akilu Herodu 3 Atipas
e.
Iyawo Karun o bi omokan oruko re Fillipi
keji ti o si je Herodu karun
Herodu Fillipi1 akoko ti a mo si Herodu kerin lo fe
Herodia ti Johanu onitebomi tako Herodu fillip Keji olo fe Salomi.
Lehin
iku Fillipi keji2 Herodu Agriipa1 loje oba dipo re lehin eyi Haris Herodu agba
lojo ba lo wo nigbati a bi Jesu ni 4B.C oba ti apeni. Herodu agba yi nigbati a
bi Jesu naa ku ni 4 B.C ati Ari to bulosi lehin re ni Herodu Aikanu joba oje
oba to buru lopolopo ti o sise buburu loju oluwa Herodu Antipas yi naa ni a le
kuro lori oye e lelo si ilu miran tori awon iwa buburu re ui ni o fi aye gba
Fillipi akoko lati joba dipo re. Herodu Fillipi akoko yi je oba ti o dara
lopolopo awon eniyan feran re bii o tile je pe Aare fidie ni. Oba mejeji kun ii
44AD
Fillipi 1, Fillipi 2 joba larin A.D3939 AD41 awon
mejeji ku ni AD44
Lehin
iku Fillipi to je fi die yi oba Herodu akkoko ni o wa fu ori oye ori ite Oba
Herodu Agrippa1 ni a kan ni iko idin di je a si pa A.A12:20-23. Lehin iku re
omo re lo Joba oun ni Agripa keji 2 leyin omo re yi Feic ati Fesitosi ki se oba
ayele ni won
IRIBOMI
JESU KRISTI
Matiu 3:13-17, Marku 1:9-11, Luku 3:21-31
Ninu awon ese oro Olorun wonyi ni ati ri bi Jesu se se iribomi iribo ti odo je
riri eniyan sinu odo to san patapata “oro yi iribomi” ni a mu jade ninu ede
Giriki Bati so ti o tunmosi sin sin, sinu odo tio o san.
ORISI
AWON IRIBO TO WA
1.
Iri bo ti odo eyi ni npe ni iribomi
2.
Iribo ti Emi mimo
3.
Iribo ti ijo
4.
Iribo ti ina
AWON
IDI TI IRIBOMI FI JE DANDAN
1.
Lati mu gbogbo ododo Olorun nse
2.
O je idaniloju pe a je ti Olorun
3.
Jesu se lati je apere fun wa
4.
O je amin idani mot i o se fi oju ara
rip e ati ba Jesu ni majemu
5.
O je amin irele si ase Jesu
6.
O je awmi pe agboran si ase Olorun
7.
O je igbese lati gbe ise ti Olorun le ni
lowo
8.
O je oun ti aun fi fi isotito wa
patatapata fun Olorun
ITUMO
IRIBO JESU
John
1:30-33
Iribo Jesu ni tumo
Pataki gege bi afiwe pelu Johanu onitebomi niwon igba ti o je wipe Johanu yi lo
se afihan Jesu gege bi olugbala araye.
Johanu ni eri ti o fidi
mule nipa eniti messiah se da olugbala araye mo (Olorun wipe lori eni ti ob ati
amin Emi mimo ti o se fi oju ara ri ri amin adaba) ti o so kale ti o si bale
eni ti o se iribomi fun eni naa ni Olorun yan lati oke eni naa Olunwa yanm lati
je olugbala araye yato wa larin irinbomi Jesu larin eyiti awon eniyan se nitori
ni gere ti a ti se iribomi fun Jesu ni orun si asiri ifaraha Emi mimo ti o si
bale Jesu lori bi adaba
IDANIWO JESU KRISITI
Mattiu 4:1-11, Luku
4:1-13, Marku 1:12-13
Nje a le dan eni ti
orun wo bi? Beni a a le dan won nitori oni okan eniyan ti a le danwo bakan na oni ara ti a le ponloju
oni ara ati irewesi Heb 4:15, Mattiu 26:38, Deu 8:1-3 Jesu ko dojuko idawon
gege bi omo Olorun ti o wa lati oke nitori a o le da Olorun wo bakanna a o le
da omore wo sugbo Jesu dojuko idanwo gege bi omo eniyan ti o gbe iseda eniyan
wo Mattiu 4:1 ninu Mattiu 4:1 ni ati ri akosile idanwo Jesu ni ibi ni a ti
gburo re ni emi meji ti won mura fun iwa ya ija.
Emi
olorun loo dari Jesus iju ni ibi idanwo emi esu losi dan Jesu wo nibe ni a ti
ri emi meji ti ko se fi oju ara ri Emi Olorun ati emi esu. Aginju je ibi idanwo
Emi
esu lo ma dan niwo sugbo emi Olorun ma se itunu isele iwe Matiu 4:1-11 ni o fi
aworan oun ti aginju je han wa oun ti a pe aginju je ibi idanwo
Olorun
ti la ona re sile pe Jesu yio bere ise iranse isegun re lori satani ati fi
ororor yan Jesu fun ise Pataki ise iranse ye naa ni lati le fo gbogbo agbara
ijoba satani lori eniyan ise Jesu lati de alagbara ni ki o si ko ni ikogun Mattiu 24, Isaiah 61:1-3
Iwariri
bo satani nigbati ori ijoba re oju ti o subu Mattiu 12:29 nitori naa Jesu ni
laity an iru Messiah ti oun yio je Josua 24:15-16 se ki o je Messiah ti o
gbanjugbaja ti gbogbo eniyan nfe tabi messiah ti a ko sile se ki o waasu alaafia
pelu Olorun tabi iwayaja pelu ijoba Romu se ki o segun pelu ida tabi pelu
agbelebu seki emi Olorun ma dari tabi emi aye yi seki o gba ojege, pelu awon
ijoba tabi ki o yara re soto fun Olorun se ki o lo gbara re fun ara re ni ona
ti ara tabi ki o lo fun imo run imukuro isoro ati idaloro eda awon ikan won yi
ni adari Jesu lati lo yanju ki ise iranse re to bere.
AWON
APOSTELI AKOKO JESU KRISTI
John
1:35-51
Johanu
onitebomi ko gbagbe pe ojuse oun ti a ran oun waye wase lati dari awon eniyan
sodo olugbala lojo kan ni gbati o rip e Jesu rekoja lo o sun fun meji ninu awon omo lehin re pe (woo
do aguntan Olorun) awon omo ehin mejeji yin i Anderu ati Johanu bi won ti gbo
oro eyiti Johanu so yi wonyi pada won tele Jesu Anderu yin i o pada mu Peteru
wa, Johanu ni o si sese ko je pe oun lo mu Jakobu egbon re wa. Jesu fun rare lo
pe Fillipi, Fillipi lomu Natanieli wa leyin eyi ni Jesu fi ipe Pataki si ita
fun awon mererin yi Peteru, Anderu, Johanu, Jakobu leyin eyi ni Jesu fi ipe pea
won omo ehin mejila awon ti a koni ni eko Jesu.
ORUKO
AWON OMO EYIN MEJILA
Mattiu 10:2-3, Marku
3:16-19, Matiu 10-2-3
1.
Peteru
2.
Jakobu agba omo Sebede
3.
Anderu
4.
Johanu
5.
Jakobu keji kekere
6.
Batilomiu
7.
Tomasi
8.
Juda tabi tadeu
9.
Simoni
10.
Fillipi
11.
Matiu agbowoodee
12.
Judasi Isikarotu
ISE
IYANU AKOKO TI JESU SE
John 2:1-11
Igbeyawo ti kanna ti
Galli ni ise iyanu akoko ise iyanu akoko yi sele nigbati awonn eniyan koti mo
Jesu
1.
Ise iyanuyi sele nigbati akoko Jesu ko
ti to nitori ako ti se afihan re
2.
Ise iyanu yi sele nitori ni ibi igbayawo
ye wainini ti tan
3.
Mari iya Jesu da si oro naa nipa sisofun
won lati lo ba Jesun ati ifitoni leti yip e (ohun kokun ti o ba so fun yin wipe
kii e se ese)
4.
Nitori pe Jesu dasi oro naa, waini ti
Jesu pe se yi dara ju eyiti iyawo ko gbe kale lo
5.
Nigati Jesu ba dasi isele kana won isele
tabi ohun mo la gbagbo ni o mon sele
6.
Pe Jesu ladasi oro aye re
7.
Eri elejo Pataki ti o pe sibi igbeyawo
naa
AWON
ORO IKONI TABI EKO JESU KRISTI
A
ko gbodo gbagbe pe Jesu je oba alalufa ati woli fun iran enijyan. Gege bi woli
Jesu koni ni ona olorun Gegebi Aalufa jesu ku fun ese iran eniyan o joba lo
awon eniyan.
Ise iranse Jesu ki o to ku lori agbelebu ni ise iran
se woli ti o koni ni liana Olorun. Awon liana ikoni Jesu ni o salaye ninu ejko
ti o se agbekele re ninu iwaasu ti ise amin ati ise iyanu si tele Mattiu 4:23
AWON
KOKO IKONI JESU KRISTI
Gbogbo ikoni Jesu Krisiti ni a se agbekale sabe iso
ri merin yi
1.
Eko nipa ijoba orun
2.
Nipa eda Olorun
3.
Nipa igbala
4.
Nipa igbe aye
Gbogbo oro Jesu Kristi won yin i ase mot i lehin
lati odo Olorun wa
IWAASU
LORI OKE
Lehin ti Jesu ati awon omo re ti waasu niipa ijoba
Olorun ti o ku si dede fun awon akoko kan Jesu bere, sin bere nipa awon ofin
ijoba yii ati wipe kinni awon eniyan fi wa bawon ni ofin se wa kin si ibasepo
ti o wa ninu oin ijoba orun yi ati ofin Mose
AWON
EKO INU MATIU 5:1-6
1.
Omo egbe jije omo ijoba naa Mati 5:1-16
a. Ipa
won Matiu 5:1-16
2.
Ihuwasi omo eniyan Matt 5:17-48
a. Ipaniyan
ati ibi
b. Pansaga
si ifekufe
c. Igbeyawo
titi ti ko si ikosile ati ikosile
d. Ibura
ati aridaju
e. Igbesan
ati ipamora
f. Ikoria
ati ife Mattiu 5:17-48
3.
Ododo Matiu 6:1-18
a. Ififuni
tabi itore
b. Awe
gbigba
c. Adura
gbigba
4.
Ohun ini Mattiu 6:19-34
Ni
abe ibi yin i awon ohun ti omo Olorun gbodo yago fun
a. Ojukokoro
b. Awon
aniyan
5.
Eko nipan Ihunwasi Mattiu 7:1-2 tabi ise
si awon ohun ti agbodo kuye si
a. Nipa
aini aka si
b. Ao
gbodo ni alailegabadura
c. A
gbodo soro nipa imo tara eni ni kan
d. Ao
gbodo je alaibikita lati se awon ohun to toni gba too to
Oro ipari Matiu 7:13-27
a.
Jesu pa owe nipa ona meji ona gboro ati
ona to oro
b.
Jesu pa owe nipa igi meji igi rere ati
igi buburu
c.
Jesu pa owe nipa ipele meji ori yarin
ati ori apata
AWON
IKONI JESU NIPA OWE (AWON OWE OLUWA)
Matiu
13:14-17
Owe
ni Jesus a ba ma lo lati fi idi ijinle otito orun han pelu aowon ikan inu aye
ti eniyan fi le loye awon owe re awon ikoni Jesun nipa owe apin sabe isori meje. Abe isorin kinni ni awon owe to ni se
pelu ijoba olorun awon ti nbe ni abe re ni won yi
1. Owe
afursugbin Mattiu 13:1-12, 18:23
2. Owe
epo Matiu 13:24-30, 37,43
3. Owe
ti woro Mustadi 13:31-32
4. Owe
ti iwukara Matiu 13:33-35
5. Owe
ti isura ti o pa mo Matiu 13:44
6. Owe
ti padi Olowo iyebiye Matiu 13:45-46
7. Owe
awon ti aiso ododo Matiu 13:47
8. Owe
ti irugin ti o hun ni ikoko Marku 4:26-28
2. EYI NI AWON OWE TONI
owe meji na ari labe
isori yi
1.
Owe asiwere oloro Luku 12:16
2.
Owe omo odo alailere Luku 16:18
3.
IPIN KETA AWON OWE TONI SE PELU ADURA
Owe meta ni be labe
isori yi
1.
Owe farisi ati agbowoode Luku 18:11-14
2.
Owe awon ore meji laarin ogan jo oru
Luku 11:5-8\
3.
Owe onidajo alaisododo Luku 18:1-8
4.
ISORI YI NI AWON OWE TO SO NIPA ORE OFE OLORUN
Awon owe meta ni a ri
labe isori yi ]
1.
Owe agutan ti o sonu Luku 15:3-7
2.
Owe owo ide ti o onu Luku 15:8-10
3.
Owe omo odo oninakuna Luku 15:11-32
5.
AWON OWE WON YI NI O SO NIPA ARA WA
Owe
meta ni ari labe isori yi
1. Omo
odo alailedarijin Matiy 18:15-20
2. Owe
alanu Samaria Matiy 10:30-37
3. Owe
okunrinn oloro ati Lasaru Luku 16:18-31
6. EYI NI AWON OWE TO SO NIPA ISE ISIN
Owe marun lo wa labe
isori yi
1.
Owe awon alagba se ninu ogba ajara
Matttiu 20:1-16
2.
Owe ayigbese meji Luku 7:41-43
3.
Awon owe Talenti Matiu 25:14-30
4.
Owe nminna mewa Luku 19:12-27
5.
Owe eniti o koi le ti ko se isiro Luku 14:25-33
7.
AWON OOWE TO NI SE PELU IDAJO
Owe mejo lowa labe
isori yi
1.
Owe igi opoto alaileso Luku 13:6-9
2.
Owe awon omo meji Matiu 21:28-32
3.
Owe awon olusogba buburu Matiu 21:33-41
4.
Owe ti ase nla Luku 14:15-24
5.
Owe ti ase nala igbeyawo oba Mattiu
22:1-14
6.
Owe Wundia mewa Mattiu 25:1-13
7.
Owe awon ti a pe wa jeun Luku 14:1-11
8.
Owe awon omo odo ti ko sona Mattiu 24:42-51
Gboggbo awon owe Jesu je ogbon o le
meji (32)
WON
TAKO ISE IRANSE JESU
Awon idi ti ise iranse
Jesui fi ba atako pade
1.
Won tako ise iranse Jesu ko awon omo
lehin jo fun Jesu n so ati kiko ti Jesu ko awon omo lehin jo fun oun ti ijoba
Olorun je oun ti o ba ibinnun ati irunu olori elesin pade
2.
Awon olori elesin fi esu kan Jesu pe se
ni Jesu ko awon tuntun jot i ko ni ati lehin ilakales kesin ati ifoowosi iwe
mimo
3.
Ofin ajti tempili je liana meji Pataki
Matiu 5:27-28 Matiu 12:16, John 15:16-17 won Jesu se atako
IMOLE
ORUN LORI AGBELEBU
Nigbati Peteru ji ti o
ri Mose se afihan ofin ati Elijah ti se afihan awon woli ti o soro peluy Jesu
ti a se imuse ofin atis woli Peteru soro jade “Oluwa jeksi a ma gbe ni ibi yi
ti o bafe” ki a pa ago meta, okan fun o okan fun Mose ati okan ti o kun fun
Elijah” (Matiu 17:4, Heb 1:1-3)
Awow ero won yin i Peteru ro ibati dara to ki won mo gbe
loke pelu awon ayanfe wonyi yato si
isale ni ibi ti awon Farisi ati awon alaigbagbo gbe wa jeki a ma gbe ni ibi yi
lati ya go fun awon akoko okunkun ti ati ijjiya ti o mbo jeki ka ma gbe ninu
ogo ti oke yii ju ki asokale si isale ni ibi iresile wa ati ikosile wa.
Ninuu ipo iran ati
asotele yi Peteru ti gbagbe pe opolopo ise lo si wa lati se ki won to le wonu
ogo (laija a ki segun, lai segun a ki
deni ni ade).
Larin awon samo to subo won yin i won gbo ohun Olorun
wipe “eyi yin i ayyanfe omo mi ema gbo tire Matiu 17:5” oro yi je ikede pe Jesu
ju ose ti se afihan ofin bakanna, Jesu ju Elijah lo ti ise afihan awon woli
nitori Jesu je omo Olorun. Jesu ni oro ati ase ti o gaju nipa oro esin Heberu
1:1-31 (“oro yi e ma gbo tire”) fi ise Pataki ranse si awon aposteli ti o ro
won wipe ki won gba oluwa wo gbo ninu eko gbogbo ti o ti ko won ati eyiti yi o
tun ma ko won ati eko nipa iku re ti yi o mu won ko se bakannaa ni baba se
Olorun ase Oluorun ni wipe ki won gbo ti Jesu koda ninu ijiya ati iku re ti
koni salai ise le
AKOKO LARIN IWASAYE JESU LAKOKO ATI
IPADAPO RE LEKEJI
Akoko ti o wa
larin iwasaye Jesu ni akoko ati ipada bo re le keji ni a mo si awon oruko won
yi
1.
Akoko ijo
2.
Akoko okunkun
3.
Akoko larin iwasaye mejeji
|
Agbelebu ijiya
|
|
Akoko ijo
|
|
Ade logo
|
|
woli
|
AKOKO
TI O WA LAARIN IWASAYE JESU LAKOKO ATI IPADABO RE LEEKEJI
1.
Akoko ijo
2.
Akoko okunkunn
AWON
IKAN MEJE TI YIO MA SELE NI AKOKO IJO
1. Awon
Juu yi tu kakiri awon orile ede
2. Ile
awon Juu yi wan i abe awon keferi titi di igba ti Olorun yio da awon keferi
lejo
3. Ni
akkoko yin i awon iranse Olorun yio ma ba ise ihin rere lo lati waasu Ihinrere
kakiri agbaye Luku 19:11-27, Mattiu 24:14
4. Yio
je akoko ti ipadebo Jesu yi fa ile Luku 18:1-8 ti o ninu yio ma ko awon eniyan
wipe ko wa mo
5. O je akoko ti opoloopo ti yio ma mura fun
ipadabo Jesu ti opolopo yio ma pada sehin mattiu 25:1-11, Heberu 10:36-39
6. Akoko
ti awon alaiso iran se olorun yio ma pada sehin won yi maso wipe oko iyawo pe
de Luku 12:45
7. Akoko
ti oko iyawo yio farahan ninu ogo Heberu 10:37
ISIN
IDAGBERE TABI OUNJE ALE OLUWA
Mattiu 26:17-30, Marku
14:12-26, Luku 22:7-30 John 13:1-30
Jesu ti mura tan tabi
lati je ase irekoja ti o gbeyin Jesu wipe elo si inu ilu eso fun Okunrinaa
(Jesu wipe akoko mi ti sun mo tosi mo si fe je ase irekoja ni ni ile re pelu
awon omo lehin mi). Iwe ihinnre ti anti owo luku ko so nipa ti won yio fi da
okunrin naa mo yio ru ladugbo omi ni ni ejika re pe oun ni ki won tele ile kele
ti won ba won lodo oluwaa re ki won si jise fun Luku 22:10-13
ORO IDAGBERE JESU
Eyini a o ri ninu John
13:35 ati wo John 14, 16, 17, 26. Oro ti Jesu so si awon omolehin re nipa lilo
si ibi kan ti won ko ti le ba oun lo nissiyi John 13:33 muki okan won darun
nitori won ronu nipa idanika wa won ati ipo alailagba ti won yi wa nigbati Jesu
ba kuro larin won.
Lati le mu ki Jesu mu won lokan le ati oro imulo igbe
lokan le ati oro igbero tabi amoran igbeniro lo muki Jesu oro idagbere fun
Eyi ti a se afihan re
ni ona kukuru yi
1.
Eni ife ara yin Jesu ba won sorod nitori
eyi ni ofin titu ati ofin ti o gbeyin ti Jesu fi fun awon omo lehin re ki o to
lo si ori agbelebu nitori nipa nini ife ara yato si ikorira iwa adani kan je ti
o gba ile aye ka awon eniyan yio mo ni tooto pe omo lehin mi ni eje
2.
Ema je jeki okan yin daru Jesu turo won
wipe nililo joun ti oun lo kuro lodo won
mu ki okan won daru Jesu tu ro won lati gba ohun gbo pelu ohun gbogbo nitori
akoko mbo ti yio soro lati gbaa ara yin boya o sese fun mi lati paro fun yin
emi ko fi ile aye sile nitori pe ile aye sunmi tabi boya iku je ikorita le ye
sugbon mo fe ile aye sile ki ife Olorun le se se
3.
Mo lo fun ete kan Pataki Jesu so pe
nitori awa omo lehin ti ko nil aye John 14:1-3 ni oun nse lo sii oorun lati lo
pese ile sile fun wa ngbati akoko basi to oun yio pada wa lati wa mu wa ki a ba
le wan i ibi ti oun wa pelu ki o ma ba si iyapa mo ema se bere ibere nipa ona
baba nitori o to fun yin lati mop e ni won igbati ibase po pelu mi bada n mo
ran ehin yio ma ma ni ore ofe si odo baba (Nitori emi ni ona kan soso, otito
ati aye tio o loso odo Olorun ti ko se foju ri) John 14:6
AWON
ILERI TI O GBEYIN
John 16:1-33
Ileri jeasu nipe oun
koni fi wa sile lain i agbara ni gbati oun ba fi aye yi sile oun yio ran
oluranlowo ti ko se foju ara ri ti yio mo je olubakegbe fun wan i gbobo igba
(Emi mimo) nipase re oun yio ma so ara re di mimo fun wa bi o tile je pe aye ko
ke rii olu bani kegbe yi ti a peni (Emi mimo) ni yi je oluko ti yio mu yin was i oju imo otito ti
yio je oluko ti yio mu yin was ii oju imo otitio ti yio ma ko yin ni ohun
gbogbo e ko ni lo lati dabobo eko ninu ogbon atii oye yin. Emi mimo ni yio ma
je asoju mi lakti mun awon eniyan mo ese won nitori won komi sile. Ti o mu won
moye pe E mi ni olododo naa, yio si mu won mope agbara ijekaba satani ni a ti
pari a sit i da satani lejo yio ma ran yin lo wo yio si ma fi agbara fun yin ni
bi e bat i pa ofin ati ase mimo ti e sile mo mi petipeti ni awon oun tie mi ti
yio mu yin so mo mi bi eka lara ajara. Ise agbara ti o le wani iwaju yin lati
se sugbon laisi mi ekole se ohun koun e ma je alagbara.
Ema se jeki o ya yin
lenu tagi ki e e ko se bi aye ga korira yin bi won bas i gbogbun ti yin eranti
bi won se se simi emit i mo je asiwaju yin ati Olorun yin ti won bat i le ko mi
won yio ko yin si se inu nibini si yin ninu aimokan ni won yio korira yin
nitori iwaasu yin ati igbe aye mimo won wi yio ba iwa agabagbe won wi ati ese
won wi ninu aye eyin yio ni iponju sugbon e tujuka mot i segun aye John 16:33
2. Nibe ni o ti gbadura pe ki o pa awon omo
lehin mo ko si ya won si mimo bi won ti wa pelu oun ninu aye
3. Jesu tun gbadura fun
awon ti yio wa lehin oun nipa awon ti yio wa lehin oun
4. Adura ikehin ti o
gba je ti awon ti yio wa pelu oun tio won yio sir i oun ninu ogo Olorun ni
adura ipajri yi Jesu ti gbadura ki won
le ni ipamora ati ifarada ti yio ke mu ki won duro de opin titi di igba
ifarahan Olorunn ninu ogo Olorun
|
SALOME
|
|
PHERORA
|
|
JOSEPH
|
|
HEROD THE GREAT
(HEROD 1)
|
|
PHARSAL
|
|
DORIS
|
|
MALTAKE
|
|
CLEOPATRAS
|
|
MARIAM OF
MACCABES
|
|
MARIAM OF BETUSIM
|
|
ALEXANDER
|
|
ARISTOBULUS
|
|
HERODII
ARCHELUS
|
|
HERODII
ANTIPASTERTACH
|
|
HERODV
PHILLLIPI II
|
|
ANTIPARTTER
|
|
KING OF
CHALIS
|
|
SALOME
|
|
HEROD IV
AGRIPPA 1
|
|
HERODAS
|
|
BERNICE
|
|
HERODVI
AGRIPPAII
|
|
DRUSILLA
AGRIPPA III
THE WIFE OF
FESTUS
ACT
24:24
|
|
ANTIPAS
|
|
ANTIPATER
|
|
AWON
MOLEBI HERODU
|
No comments:
Post a Comment